lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu tope alabi – oruko oluwa

Loading...

maa yin o, olorun t’o dara, t’o n s’ohun gbogbo fun mi o
emi o yin o, imole to n f’ona han mi oo e
ore re koja siso, o kamomo eee

ona re ma pe mi o, arinye ni o
eeee (t-tobi oga nla)
alade ogo, iba re o
olorun to dara, iwa re wu mi o e
mo wa, mi o ri oba to dabi re ninu gbogbo oba
alade ogo, iba re o
olorun to dara, iwa re wu mi o e
mo wa, mi o ri oba to dabi re ninu gbogbo oba
awon t’orun n f’ogo fun un, elemi eda
o na’wo re lat’orun ja aye o
o n rin lori igbi okun
oruko re nikan lo ko aje ya
agbara re nikan ni ko le pin
ko s’eni to le gb’ogo re pin lailai
alade ogo, iba re o
olorun to dara, iwa re wu mi o e
mo wa, mi o ri oba to dabi re ninu gbogbo oba
alade ogo, iba re o
olorun to dara, iwa re wu mi o e
mo wa, mi o ri oba to dabi re ninu gbogbo oba
gbogbo aye n wariri labe re
eda gbogbo o lo gba o loga
ohun gbogbo to da lorun at’aye
ko le ri’di agbara re o ee
won o le ri’di agbara re o, aseda mi
alade ogo, iba re o
olorun to dara, iwa re wu mi o e
mo wa, mi o ri oba to dabi re ninu gbogbo oba
alade ogo, iba re o
olorun to dara, iwa re wu mi o e
mo wa, mi o ri oba to dabi re ninu gbogbo oba
oluwa oluwa, oruko re niyi
ni gbogbo aye o, oruko re niyi
ninu awon orun o, oruko re niyi
apeepetan, oloruko pupo
t-ti lailai, oruko re ko le pin
t-ti aye, oruko re ko le pin
oluwa oluwa, oruko re niyi
ni gbogbo aye o, oruko re niyi
ninu awon orun o, oruko re niyi
apeepetan, oloruko pupo
t-ti lailai, oruko re ko le pin
t-ti aye, oruko re ko le pin
alagbara, olododo, atobiju loluwa
alaanu o loluwa, oruko re n gba ni la
oruko re n gbe ni ro, oruko re n so ni d’oloro
oloruko aperire (aperire apedahun loruko jesu)
oluwa oluwa, oruko re niyi
ni gbogbo aye o, oruko re niyi
ninu awon orun o, oruko re niyi
apeepetan, oloruko pupo
t-ti lailai, oruko re ko le pin
t-ti aye, oruko re ko le pin
oruko re n ja fun ni
oruko re n gbe iku mi
oruko re n f’ona han ni
oruko re n t’aye se
ibi gbo’ruko re, o pare
okunkun gbo o wole lo
oluwa oluwa, oruko re niyi
ni gbogbo aye o, oruko re niyi
ninu awon orun o, oruko re niyi
apeepetan, oloruko pupo
t-ti lailai, oruko re ko le pin
t-ti aye, oruko re ko le pin
oruko ti ko le baje, ni mo be’ri fun
oruko ti o le pin, tion sir!
oruko oluwa o, ile iso
oruko oluwa ni ipa, agbara ni
oruko, oruko, oruko, oruko, oruko nlanla
emi ni, ona
ot-to, iye
ilekun, kokoro
imole, ododo
jesu kristi, messiah
okuta aidigbolu, odo aguntan rere
apata ayeraye e


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...