lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu tunny prince - sneh!

Loading...

o ṣá mọ… hehe
lion boyz rugged flows
it’s mizta sternz
oya wake up, kosi time
ogade shut up hold your mouth
if you no wan hold your lips
ogade shut up,ko lọ shout
oya sneh beat, sneh the ah!
ẹ lè gb’omo wọlé láti corner
oya sneh your girl, sneh your babe
oya sneh beat, sneh the ah!
ẹ lè gb’omo wọlé láti corner
oya sneh your girl, sneh your babe
lion sneh, to tun ko sneh
ama kọrin sneh, bobo sneh
incase you don’t know, ọlọ́hun sneh
lati kékeré ni mo tin hustle, wọn sọ fún mi pé kín jarami sneh
and am asking for the way out, wọn sọ fún mi pé kín ṣe yahoo sneh
and some people talk so mi o lọpọlọ make i no do am, kinse koso sneh
oya sofunmi ṣe na koso past yahoo, àbí na yahoo sneh
wọn ní ìbéèrè, ìbéèrè, ìbè… ìbè… ìbéèrè
them say na question, na question, na que… na que… na question
sneh things on point, o máa ń, jawo gan
ọmọ ton sọ, to ti kọrin gan
…ah!
oya wake up, kosi time
ogade shut up hold your mouth
if you no wan hold your lips
ogade shut up,ko lọ shout
oya sneh beat, sneh the ah!
ẹ lè gb’omo wọlé láti corner
oya sneh your girl, sneh your babe
oya sneh beat, sneh the ah!
ẹ lè gb’omo wọlé láti corner
oya sneh your girl, sneh your babe
wọn ti sanwó wọlé láti marley
make una look, mi ò kinse ninje
ama má jó, ama yo, kele mọ p’oluwa tise
s’omo mr. check issa goalkeeper
s’omo torres àti ballack
to man gege bìtì kaka
o ma yawon lenu biti van~persie
to ba de show, wọn ma gbenusi
but ko mean pe that is not good
ye ma ṣeré kéré, bìtì kanu
oya wake up, kosi time
ogade shut up hold your mouth
if you no wan hold your lips
ogade shut up,ko lọ shout
oya sneh beat, sneh the ah!
ẹ lè gb’omo wọlé láti corner
oya sneh your girl, sneh your babe
oya sneh beat, sneh the ah!
ẹ lè gb’omo wọlé láti corner
oya sneh your girl, sneh your babe
oma ase mawo e sa, seni efe dayanmo nii
o mọ mikky, oshe


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...