lirik lagu tmp - oluwa
{intro}
oh lord of mercy…..
paranranrara!!!
imole! mohbad…
oluwa jowo o, oluwa 3ce
{verse 1}
oluwa sign soro me o (oluwa sign soro me o)
oluwa dakun se temi funmi
oluwa gbo adura me o (oluwa gbo adura me o)
baba so n gbohun me o
oluwa bless hustle me o (oluwa bless hustle me)
oluwa dakun maje n lo lofo
igba wo ni ire ma kan me o (igba wo ni ire ma kan me o)
baba so n gbohun me o
{hook}
oh oh oh baba ti ba mi se
oni ki n ma lo, ki n ma lo , ki n ma lo
ki n lo ma jubilate, yea yea
baba ti ba mi se
oni ki n ma lo, ki n ma lo , ki n ma lo
ki n lo ma celebrate, yea yea
ko si ewu funwa, omo olorun lawa
e o le deru bawa, ojojumo lo fi n gbo adura wa
ko le doju ti awa
{verse 2} mohbad
ko si ewu funwa, omo olorun lawa
e o le deru bawa, ojojumo lo fi n gbo adura wa
ko le doju ti awa
aiymoye pains ti mo go thru
aiymoye dreams ti mo chase ti ko come true
aiymoye emi n~gg a se to de ti sonu
base on say won fe pa owo yi se won de fe hustle
mo bere orin kiko layi si eni to mo mi
aiymoye rapper battle to ti mono to je pe omomi
ere lo pe abi woh no be small story (small story)
sugbon today me i give god the big glory (the glory)
aiymoye oro werray to ti so leyin me
sugbon nisiyin wo so pe awon fe feature me
elo lo wa nle won so pe no money
ti o ba ti si ooo wa ma lole bye bye
kos sewu fun omo olorun lawa
e o le deru bawa
ojo jumo lo n fi gbo adura wa
ko ma le doju tawa
oh oh oh…
{hook} tmp
baba ti ba mi se (bami se)
oni ki n ma lo, ki n ma lo , ki n ma lo
ki n lo ma jubilate, yea yea
baba ti ba mi se (bami se)
oni ki n ma lo, ki n ma lo , ki n ma lo
ki n lo ma celebrate, yea yea
baba lo ni ki n ma lo…… eh
owun lo ni ki n ma lo ….
ko ma de si ewu lono
baba lo ni ki n ma lo ooo
owun lo ni ki n ma lo
ki n somo lo, ki n gbomo lo
ninu aye
its stg
{outro}
imole {mohbad}
ko ma de si ewu lono
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu andré (duo) - prima iubire (remix)
- lirik lagu moumoon - butterfly effect
- lirik lagu prince bopp - chosen one
- lirik lagu the murar - попота 2 (popota 2)
- lirik lagu wezen - fzn
- lirik lagu soul xo! - мне плевать (i do not care)
- lirik lagu kungfu rick - the crumbling..
- lirik lagu chikili tubbie - parte de tu mundo (bonus track)
- lirik lagu svoje - 4 su sata
- lirik lagu marcus rogers - holy one