lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu temitope serentainer - jesu awa yio sin o (ccc hymn 62)

Loading...

jesu
àwa yíò sìn ọ′
jesu
àwa yíò sìn ọ’
n′íbi mímọ’ yìí
l’áàrin ìjọ nlá rẹ
àwa yíò sìn ọ′
títí d′ópin
àwa yíò mú ‘bùkún re′lé
jesu
àwa yíò sìn ọ’
jesu
àwa yíò sìn ọ′
n’íbi mímọ′ yìí
l’áàrin ìjọ nlá rẹ
èmi ó sìn ọ’
títí d′ópin
èmi ó mú ′bùkún re’lé
jesu
àwa yíò sìn ọ′
jesu
àwa yíò sìn ọ’
n′íbi mímọ’ yìí
l′áàrin ìjọ nlá rẹ
àwa yíò sìn ọ’
títí d’ópin
àwa yíò mú ′bùkún re′lé
àmín


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...