![lirik.web.id](https://lirik.web.id/tema/logo.png)
lirik lagu teledalase - the ones who didn't die
a’udhu bi kalimaat~illaahit~taammah
min kulli shaytaanin, wa haammah
wa min kulli ‘aynin laammah
a’udhu bi kalimaat~illaahit~taammah
min kulli shaytaanin, wa haammah
wa min kulli ‘aynin laammah
oba ma je n soonu o
oba ma je n soonu o
oba ma je n soonu o
iji aye, aye yii po o
imole da wami ri
imole da o
imole da o
iji aye, aye yi po o
oluwa da abo bo mi
da abo bo mi
ma je n rinu o
ma je n rinu o
iji aye, aye yii po o
adele ba ire
arina ko ire
akoya ibi
je n mu’re dele
adele ba ire
arina ko ire
imole da wami ri
imole da o
imole da o
o ba mo je n soonu o
nítorí wón de àwòn sílè fún mi láinídi
wón si gbé kötò sílè dè mí láinídií
jé kí iparun dé bá won lójiji
jé kí àwòn tí wón de sílè dè mí mú won
jé kí wón kó sinu rè, kí wón si parun!
nígbà náà ni n óo máa yò ninu oluwa
n óo sì yo ayò lá nítorí igbalà rè
n óo fi gbogbo ara wí pé
oluwa, ta ni ó dàbí re?
iwo ni ò n gba aláîlágbára lówó eni tí ó lágbára
tí o sì n gba aláilágbára ati aláiní
lówó eni tí ó fé fi wón se ìje
oluwa saanu funmi
mo bèèbèè
imole da wami ri
imole da o
imole da o
okunkun aye, aye yi suu o
imole o
imole o
imole
a’udhu bi kalimaat~illaahit~taammah
min kulli shaytaanin, wa haammah
wa min kulli ‘aynin laammah
a’udhu bi kalimaat~illaahit~taammah
min kulli shaytaanin, wa haammah wa min kulli ‘aynin laammah
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu viki mosxoliou - όπως mε ξέχασες θα σε ξεχάσω
- lirik lagu hoodbaby peppa - dancing with the devil
- lirik lagu kazel - saw
- lirik lagu yoki - przytyk 2009
- lirik lagu rafael escalona - la vieja sara
- lirik lagu rael, mano brown & dom filó - onda (citação a onda)
- lirik lagu huntori martine sento - mon pays me manque
- lirik lagu binz da poet - duyên kiếp cầm ca
- lirik lagu zac chase - quick predicament
- lirik lagu ivory mae - for wanting to feel