![lirik.web.id](https://lirik.web.id/tema/logo.png)
lirik lagu teledalase - odun nba ku
óyeku mo bá ó mu lè má ma shẹy damì
ìnu bìbì èru ní n pa èru édò fufu ìwofa nì pà ìwófa
adifa fun ofua niìgba tí n bẹ la rìn òtá ayé bì ku
ba n se gbe mi pa oto ni ki oyè ki o ma sa mi si
bi arun sé egbe mi se oto ni oyé ko masa mi si gbò gbó alawe obi ni iku n pa oto la yo ofu a si
ìku ma pa awo mo iku ye lori àwò ọto
la yo ofu á óbì si, ìku má wó mó ìku ye lórì áwò
óyeku mó ba ó mule mama se dami ìku remì kete iku ye lorí mí
ìku mama sé ya lodede mí ori mì ma se gbá
ìku mama sé ya lodede mí ori mì ma se gbá
ó dun n ba ku ma a raso, ódun n ba ku ma a raso odun n ba ku oo
n o wọ sayan odun n ba ku ó n ó mómó yò òòòò
n o wọ sayan odun n ba ku ó n ó mómó yò òòòò…
ódun n ba ku n ó ma sógè, ódun n ba ku!
o ma fi ìle pon otì odun n ba ku ó n fi ona roka n ọ yọ sese
o ma fi ìle pon otì odun n ba ku ó n fi ona roka n ọ yọ sese
ódun ba ku o!2ce n o yo sese
ódun ba ku o!2ce n o yo sese
kin pe bi pepe tin pe kí n gbó kín tò, ki n fi ówọ pe wu ki fí eri gì jọ bì
kí ku re mì kete oooo ìku re mì kete óóó
ìku ma ma se ya ló dede mi ooo. iku ye lori mi ooo
ìku ma ma se ya ló dede mi ooo. iku ye lori mi ooo
óyèku mó ba ó mule mama se dami òbá má má sẹ dá mììì ooo
ódun n bá ku óóóó. má rá áso má bórí2ce máru bò ópè
ódun n ba ku òòò! n o mo yọ n ó mòmò yo! ìku re mì kètè iku yé lorí mì
ódun n ba ku òòò! n o mo yọ n ó mòmò yo! ìku re mì kètè iku yé lorí mì
óyẹku mo bá ó mulẹ mámá sé dámì óóó!
óyẹku mo bá ó mulẹ mámá sé dámì óóó!
iku mapa awó mó iku yé lórí awó
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu sovereign grace music - leaning on the everlasting arms (live)
- lirik lagu ash jetson - traveler.
- lirik lagu sina saedi - dream by the sea
- lirik lagu baby cute - florida (snippet 02.02.2025)*
- lirik lagu frick! - haunted!
- lirik lagu pl - pfütze
- lirik lagu sarm? (lostangel) - running on the edge
- lirik lagu mutual benefit - glow worms
- lirik lagu lolratz - animal parade
- lirik lagu code80 & euro5tar - ефир (efir)