lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu teledalase - ilé koko

Loading...

agbalagba mo sokele o
mo ti doyo
oyo alaafin
mo ti dosogbo
osogbo ilu aro
mo ro oluode
mo wa iya mi lo
won ni iya mi n be ni sabo
mo rekete
mo sa fejo
olowo laye n fe
mo rekete
mo sa fejo
olowo laye n fe
nba ti mo
nba ma ti lo o
nba duro sile
nba ti mo
nba ma lo o
nba duro sile
ile o o o o
ile o o o o
ile koko n tagbe
tagbe
ile o o o o
ile o o o o
ile koko n tagbe
tagbe
mo de sabo
sabo mo n wa iya mi
won n re oloke meji
iragbiji oloke meji
tako tabo loro agba
mo n lo
kabiesi
mo dele aresa
omo feni si
ni n bi iresa nu
won lomo tani mi o
mo lomo aresa ni mi
nba ti mo
nba ma lo o
nba duro sile
ile o o o o
ile o o o o
ile koko koko n tagbe
tagbe
ile o o o o
ile o o o o
ile koko n tagbe
tagbe
emi lomo aresa
omo feni si
ni n bi iresa nu
wole o bupo ya mi o
ya mi o
ile koko n tagbe
tagbe
mo de ikole
mo n bere iya mi
oba loni ka rogi laso
nba ti mo
nba mati lo o
nba duro sile
ile o o o o
ile o o o o
ile koko koko
n tagbe tagbe


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...