lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu teledalase - ayanfe

Loading...

mo ni ife re nitooto
n ‘o puro
n’o puro oo
mo mo ogbe okan re nitooto
amo emi yato oo
n ‘o puro
n o gbe o rin do
ese re oni kan ‘mi
n o ba o roke
ese re oni kan le
mo shey ogbingbin
je n ba o lo
ibi o ba nnlo
n ‘o ba o re
n ‘o ba o re
ayanfe, je n ba o rele oo
ibi o ba nlo
n o ba o lo
n o ba o lo
won ni ki layanmo mi
mo ni iwo ni
won ni ki layanmo mi
ife re ni
irin wa ti di ajorin
ebo wa ti di ajogbe
n o puro oooo
n o puro ooo
n o gbe o rin do
ese re oni kan mi
n o ba o ro ke
ese re oni kan le
ayanfe jen ba o dele
ibi o ba nnlo
ibi o ba nnlo
ayanfe jen ba o dele
ibi o ba nlo oo
n o ba o lo ooo
ila lomo oriki ila oooo
ogiri lomo oriki ooobe ooo
ayanfe dakun dabo shey temi
ibi o ba nnnlooo ooo
ayanfе, ayanfe ee mi
ayanfe je n ba o dеle oo
ibi o ba nnlooo
ibi o ba nnlo oo
ayanfe dakun shey temi
irin wa ajorin
ebo wa ajogbe
iku wa ajoku
(keyboard sounds)


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...