
lirik lagu rybeena - amapiapala
intro
(m~m~murderer)
(rybeena dè, rybeena dè)
(agba singing ti dè, ojurá wọn lọ, t′ijakádi kọ)
verse
mo gbè ekelebe wọ club, o mu bellaire (oh)
l’ábá dè′lè tàn, l’obá lọn ṣhèèpo (what?)
t’oba jẹrèkere, stop, mio bá ẹ fẹyin
sáárè funmi l′ori, ọmọ, time dey go
don′t please my heart, please my body
ṣh’omọ pè ọlọmọge yápá nigboro
i no fit lose my feelings for the benjamin
you no fit enter me, ayy~ahh
chorus
ṣho mọn ro, n~gga mi? (oh~ohh)
ọmọ, ko sijá ni church, ṣ′ádurá, kin ṣ’ámin (oh~ohh)
ọmọ ọpẹ no fit give up, ko ṣhati ri lapii (oh~ohh)
ṣhèbi ọrẹ n~gga mi kàn l′ofi colo yi backii
l’obá tun kigbè “gbámi gbámi” oh
hook
ẹ wá wo olè, ájibolè
o ni, ko kin ṣh′olè, ori, l’ogbè
ẹ wá wo olè, ájibolè
o ni, ko kin ṣh’olè, ori, l′ogbè
iṣho baba ruka, èyin lo yọ, ẹmi o bọ
iṣho baba ruka, èyin lo yọ, ẹmi o bọ
chorus
ayy~ah, ṣho mọn ro, n~gga mi? (oh~ohh)
ọmọ, ko sijá ni church, ṣ′ádurá, kin ṣ’ámin (oh~ohh)
ọmọ ọpẹ no fit give up, ko ṣhati ri lapii (oh~ohh)
ṣhèbi ọrẹ n~gga mi kàn l′ofi colo yi backii
l’obá tun kigbè “gbámi gbámi” oh
hook
ẹ wá wo olè, ájibolè
o ni, ko kin ṣh′olè, ori, l’ogbè
ẹ wá wo olè, ájibolè
o ni, ko kin ṣh′olè, ori, l’ogbè
iṣho baba ruka, èyin lo yọ, ẹmi o bọ
iṣho baba ruka, èyin lo yọ, ẹmi o bọ
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu pretty stooked - wanted
- lirik lagu dews pegahorn - flirt with a gun
- lirik lagu sanae (fra) - tchiki
- lirik lagu şiir! - çırılçıplak
- lirik lagu every - only want me
- lirik lagu erika roff - солнце (sun)
- lirik lagu fogo no pé - labareda de fogo
- lirik lagu sunny joshi - dark side of my mantlepiece
- lirik lagu polar island parkway - alberta (alternate version)
- lirik lagu finley - i miei amici (ft. punkreas)