lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu psalm bee - kanipe

Loading...

uh, yeah
alubarika l’ọmọ

ipokipo to ba wa dupẹ lọwọ oluwa
everything is possible with adura
only you dey form say na you sabi pass
my cup runneth over na grace full am
you no gats be jesus to face judas
as long as e dey pay, ọmọ just dey do am

(uh~uh, uh~uh)

kanipe
kanipe
kanipe
kanipe
ọmọpẹ ti l’owo

kanipe
kanipe
kanipe
kanipe
ọmọpẹ ti gbera

wọn ni pe, ki ni ma sọ
wọn ni pe, ki ni ma sọ
ọrọ kini wọn tun wi
wọn ni pe, ki ni ma sọ
wọn ni pe, ki ni ma sọ
ọrọ kini wọn tun sọ
ishẹ oluwa ko s’ẹni to ye
ishẹ oluwa ju t’alfa lọ
ishẹ oluwa ko ma s’ẹni to ye
ishẹ oluwa ju t’alfa lọ

that’s why i dey call on jehovah
(jehovah)
even anytime wey i sober
many people act like it’s over
laiye ti mo wa, ma jẹ ọn koba mi

ipokipo to ba wa dupẹ lọwọ oluwa
everything is possible with adura
only you dеy form say na you sabi pass
my cup runneth over na grace full am
you no gats bе jesus to face judas
as long as e dey pay, ọmọ just dey do am

(uh~uh, uh~uh)

kanipe
kanipe
kanipe
kanipe
ọmọpẹ ti l’owo
kanipe
kanipe
kanipe
kanipe
ọmọpẹ ti gbera

wọn ni pe, ki ni ma sọ
wọn ni pe, ki ni ma sọ
ọrọ kini wọn tun wi
wọn ni pe, ki ni ma sọ
wọn ni pe, ki ni ma sọ
ọrọ kini wọn tun sọ

ibi ori fẹ ma gbeni de, lo ma gbede
steady mo ma n hustle lojojumo mi o ṣ’ere
my mummy dey tell me wipe, surulere eh
emi o ma kere, hustle kin le re re
if i be footballer, i go don dey ball like jayjay
hustling for payday emi o wa shere
to the most high, give my thanks and my praises

kanipe
kanipe
kanipe
kanipe
ọmọpẹ ti l’owo
kanipe
kanipe
kanipe
kanipe
ọmọpẹ ti gbera

wọn ni pe, ki ni ma sọ
wọn ni pe, ki ni ma sọ
ọrọ kini wọn tun wi
wọn ni pe, ki ni ma sọ
wọn ni pe, ki ni ma sọ
ọrọ kini wọn tun sọ

written by: bello oluwatosin samuel


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...