lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu pelumi adeleke - ràn mí lówó

Loading...

mi o leni kan kan afiwo (i don’t have anybody except you)
wa ran mí lowo (come and help me)
moti sare kakiri (i’ve ran around looking for help)
mi o reni kan kan, ti o ran mí lowo (i couldn’t find anybody that will render help)
moti lo soke sodo (i’ve went up and down)
mi o reni kan kan, ti o ran mí lowo (i didn’t find anybody that would help me)
ore ofe re, oluwa mi, ni mo toro fun (your grace my lord, is what am asking for)
aanu re baami, ni mo bebe fun (your mercy is what am begging for)
laisi iranlowo oluwa (without the help of the lord)
asan ni gbogbo ilakaka mi je (all my efforts are in vain)
laisi iranlowo oluwa (without the help of the lord)
ofo ni gbogbo wahala mi (all my struggles are in vain)

i need your help o lord, come to my aid
without your help, o lord, i can do but nothing

© worshipper’s tribe


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...