lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu oriyomi kehinde - salat

Loading...

emi tigba f′olohun
pelu annabi re
t’asiko irun ba tito
emi a tun lo kirun
tinba wa kirun tan
ma tunwa s′assalatu, fun muhammadu
oremi o rjeka jo lo o
kajo s’assalatu fun, muhammadu, kajo s’assalatu fun
muhanmmad ha~mim
kajo s′assalatu fun
toha wa ya~sin
kajo s′assalatu fun
emi tigba f’olohun
pelu annabi re
emi tigba f′olohun
pelu ojise re
t’asiko irun ba tito
emi a tun lo kirun
tinba wa kirun tan
ma tunwa s′assalatu, fun muhammadu
oremi o jeka jo lo o
s’assalatu fun, muhammadu, kajo s′assalatu fun
muhanmmad ha~mim
kajo s’assalatu fun
toha wa ya~sin
kajo s’assalatu fun
oya jekalo kirun, asiko tito
je kalo kirun, asiko tito
irun subuhi, zuhri, pelu asri
magrib, hishai, ka seyen lojumo
toba d′ojo jimoh ka delo ki jimoh o
kajo rire olohun gba o
eje kalo o
kalo s′assalatu fun
fun muhammadu, kajo s’assalatu fun
muhanmmad ha~mim
kajo s′assalatu fun
toha wa ya~sin
kajo s’assalatu fun
brother won sope ke kirun, e de wa sope iro
e ni tinu bati mo o, pe′run o pan dandan
awe tun de eo tun gba, e de tun ns’agidi
kiwa lefe so lorun, pewa se laye
kiwa lefe fi jabo, l′aliqiyama o a, eje kalo o
kalo s’assalatu fun
fun muhammadu, kajo s’assalatu fun
muhanmmad ha~mim
kajo s′assalatu fun
toha wa ya~sin
kajo s′assalatu fun
sister won sope ke kirun, eyin gan sope iro
e niwa lesin tiwa bati dara, irun kiki ko
p’opo eniyan lo nkirun tio lonu mimo
wa je kin nje ko ye e o, komo daju, iwa dabi ile ni, irun ni kokoro
e tun ma bami kalo f′alaye ni kikun
oya jekalo kirun, asiko tito
je kalo kirun, asiko tito
irun subuhi, zuhri, pelu asri
magrib, hishai, ka seyen lojumo
toba d’ojo jimoh ka delo ki jimoh o
kajo rire olohun gba o
eje kalo o
kalo s′assalatu fun
fun muhammadu, kajo s’assalatu fun
muhanmmad ha~mim
kajo s′assalatu fun
toha wa ya~sin
kajo s’assalatu fun
mayo ese mi kuro loju ona re
oju ona re, lemi o ma wa titi aye
f’alijanna re s′esan tiwa tesin mi
mayo ese mi kuro loju ona re
oju ona re, lemi o ma wa titi aye
f′alijanna re s’esan tiwa tesin mi


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...