lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu oluwatunmise awoyemi - pa mi mo

Loading...

chorus: kiki eni o pamo
‎ loyo ninu ewu gbogbo oh oh
‎ s’abomi, pamimo o
‎ ki nmase s’ode ja.(3ce)

‎”oluwad! lowo re ni no fi emi mi le.”

‎verse 1: jesu mi
‎ alaabo gbogbo oh oh
‎ s’abomi, pamimo o
‎ ki nmase s’ode ja.(2ce)
‎ (back to chrs)

verse 2: abo emi at’ara tire ni
‎ pamimo o, ki nmase s’ode ja
‎ atilo, atibo, oluwa tire ni
‎ pamimo o, ki nmase s’ode ja
‎ jesu mi
‎ alaabo gbogbo oh oh
‎ s’abomi, pamimo o
‎ ki nmase s’ode ja.(2ce)
‎ (back to chrs)(2ce)
‎”dawa si oluwa

‎verse 3: ohun gbogbo ni mo file o lowo, oluwa
‎ pamimo o, ki nmase s’ode ja
‎ olorun aabo ile goseni, oluwa
‎ pamimo o, ki nmase s’ode ja
‎ (back to chrs)(2ce)

‎”dami si tiletile”


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...