lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu oluwamillar - olorunsogo

Loading...

[intro]
josco, how far?
jẹ ki n sare ja ẹ ṣiṣẹ yẹn
ehn, mo kan fẹ sare sọ story kan fun ẹ ni
in all sha, toba lọ, o lọ niyẹn o
like
life goes on, life continues
you gaz dey, o gbọdọ maa dupẹ fun life, o ye ẹ
every time, every second

[verse 1]
e for end s’olorunsogo
march 12, 2024 ni osogbo
townhall ti mo design ni mo lọ submit
coming back lori okada lo wọ nnkan mi
little kid kan lọ ja ‘na
at’emi ati bikeman olorun ni o ja daran
there and then ni ‘lẹ lẹ mo wo ‘ke, mo ke my sati
oṣe ọba to jẹ ki n casually di casualty
ki ni wọn ba sọ fun mama nurse, mummy favour?
ki ni koba da gbogbo ‘lakaka all the labour?
bike lost balance, go my knees, o di koba
like say i wan do drogba knee slide, ọmọ, lori coal tar
gbogbo knees mi bruise, ẹgbẹ mi graze
say man still dey, ko yemi na his grace
mo ro fun emma, o lo yẹ ki n lọ ṣe testimony
well, allahu o ṣe o, mo tun ti fi kọ 16, herе’s the story
[hook]
lawurabi w’ọla mami
loke maa ni, bami ṣ’amin
as i step out protеct my steppings
da ‘bo bo mi o

[verse 2]
na wetin i go chop i been dey find
wetin wan chop me been dey hide
i been no code e been dey run man trail behind
b’ara adugbo ṣe mi n shout da sigbe baii
mo yapa wo, y’ẹsẹ wo, ṣe the bros still ṣi le fly?
plus i been carry one ẹgbọn tuntun laptop
b’ọta fun ‘ju pack up, men for kuku maa sọ
them for open bag, see am say na juju catch up
ọsẹ to wẹ ni ko renew, the voodoo act up
wọn ba tori ọta ọmọ lọ wọ black black
ọsẹ ọba nla, o jẹ game ‘wọn ọta wa
o ti la ni ribi l’aye, a maa ri rere
abiamọ o ki n gb’ẹkun ọmọ rẹ ṣa ko maa tatiwere
mo ro dreams, mo ro fears
gbogbo things to ko tears
mo wo up, mo wo down, tears dropped fi my eyes
uhn, tears dropped fi my eyes
l’otitọ l’ododo aye lọja, mo tun realize
lawurabi w’ọla mami
loke maa ni, bami ṣ’amin
as i step out protect my steppings
da ‘bo bo mi o
[hook]
lawurabi w’ọla mami (s’olorunsogo)
loke maa ni, bami ṣ’amin (march 12, 2024 ni osogbo)
as i step out protect my steppings (4pm l’olorunsogo)
da ‘bo bo mi o (march 12, 2024 ni osogbo)
lawurabi
loke maa ni
as i step out
da ‘bo bo mi o

[outro]
ọ́ mọ lọ ‘re, ọ́ mọ bọ̀ọ ‘re
ìkọ́ kìí kọ́
‘bálá, èèdì kìí di ejò
agara kìí dá nu iṣẹ́ ọlọun
torofíní l’adìẹ bọ̀ oko èèmọ́
l’áyọ̀ tobá lọ lọ̀ọ́ de
ìkọ́ ò ní kọ́ ọ
èèdì o ní dì ọ́
ó rí rere ṣe
ó ri rere gbà
orí rere ni tìrère
ìrère kìí l’órí agb’ẹ́rù le
orí rere ni tìrère
ọ̀nà rẹ ó d’ire
gbogbo ohun o bá f’ọwọ́ rẹ mú
ẹ̀jẹ́ ni ó mọ jẹ́
àṣeyọrí ló mọ ṣe
àṣeyè ló ṣe
nítorí àṣeye l’alákàn ńṣe


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...