
lirik lagu musiliu haruna ishola - opon apala ti sun
[verse 1]
ẹ mi a gbọ o, ẹyin ẹlẹgbẹ, mo ni
“iṣẹ ti kaluku ba ti mọ ni ko ma tẹ’pa mọ o,” musiliu, awa lalapala gidi
tunde
apala gidi la wa n ṣe, lọjọ to ti pẹ, ọna ti jin
o ti rọ wa lọrun gan~an bi ẹkọọọ
apala gidi la wa n ṣe, lọjọ to ti pẹ, ọna ti jin
o ti rọ wa lọrun gan~an bi ẹkọ
ẹni a julọ o mọ, ara loju ọpọn
t’ọn ba n tan ẹ, jọwọ, ko ma tan ra ẹ
iru ọkẹrẹ lo~un mi a m’aja l’ẹru
oun t’ẹ o le ṣe l’ẹ n ra’wọ le ipa pin
atọka, atọka iru wọn niun ile orin
ẹru oloko awa ni wọn jẹ, aa ki ṣ’ẹgbẹ wọn n’inu ile orin
aa ki ṣ’ẹgbẹ wọn n’inu ile odu o
bo jẹ ti ka kọ’rin, ishola ni baba, o~ay
b’ẹ fẹ ṣere apala gidi
ẹ kora yin papọ, k’ẹ mi aabọ o
ki ẹ wa farabalẹ kọ’ṣẹ ọdun mẹta, o~ay
mo ti sọ tẹlẹ tẹlẹ pe tunde ishola ni president fun awọn alapala
ẹ pe musiliu ishola ki n gbọ s’eti
musiliu, musiliu o, musiliu mi babatunde
ki o gbo, ki o o tọọ
ẹyin ni presidenti fun awọn olorin apala
ni t’ile~t’oko
maa wi nibi o ba n rin, ka ba ẹ lọ, ẹru o ba wa
b’ẹru ba n bayin, ẹwi fun wa, niṣo loju ogun bo lọmọ ogun
niṣo loju ogun b’o lọmọ ogun, ẹyin ni o wo, ishola egungunjọbi
orukọ ro’ni a pe ja n ja ẹniyan
ki ni n ba jẹ gba gbe, alhiaji. orire
ọkọ raṣidatu, ọkọ wosila, ọkọ atinukẹ
baba ọlamilekan to n bẹ ni germany, baba mujira, baba. kunle
ẹgbọn y.k yẹkini mi, yẹkini, ọrẹ liasu awolesi
awo isaru odubanjọ alias oyoyo
imulẹ opo neni, yẹkini, ọmọ ṣoda
ọmọ ogbeyunu, aburo alhiaji mi, ṣoda
ṣoda, oluwa lo ran ẹ ṣe, ẹda kan, bo ṣ’eyan a ti goke ọla d’ana o
orukọ ro’ni, ẹni fẹ’re ko wi
alhiaji shuaibu, ọmọ ṣoda, alias orire
o fowo m’ẹbi m’ara, o tun mọ aladugbo, mo tẹ’ri ba fun, ọlọjọ gbogbo
oyinbo eni mọto, ile lo b’ọla, ‘aaji orire, ẹnikan o le ga o~ay
k’awọn ọlọtẹ ma ri sọ si, orire to n jẹ shuaibu, ki o gbo, ki o tọ
ki ni n ba jẹ gba gbe idowu ọlatunji
awo bebesila ti n jẹ saidi mi
awo kẹhinde, ọmọ sh~ttu~sh~tta
awo elewurẹ, gbogbo wọn pata, omo adeṣina mi, ajayi
ẹ ṣe itọju wọn, akeem mi, kagunko
idowu ọlatunji, jẹ ka sọ fun wọn wipe
[chorus]
b’aiye ba ti n yii, ka ma bawọn yi
ọpọn apala ti sun finally, o ti kuro ni t’atijọ
ishola tunde musiliu, ayinla mi joshua o
ẹ jọwọ, ẹ ba mi daa’lu bo’lẹ, alujo ni kiya mọsa
[instrumental]
b’aiye ba ti n yii, ishola, ka ma bawọn yii
ọpọn apala ti sun finally, o ti kuro ni t’atijọ
ishola tunde musiliu, ayinla mi joshua o
ẹ jọwọ, ẹ ba mi daa’lu bo’lẹ, alujo ni kiya mọsa
[instrumental]
b’aiye ba ti n yii, ishola, ka ma bawọn yii
ọpọn apala ti sun finally, o ti kuro ni t’atijọ
ishola tunde musiliu, ayinla mi joshua o
ẹ jọwọ, ẹ ba mi daa’lu bo’lẹ, alujo ni kiya mọsa
oju wa ni o ṣe, baluwẹ to l’oun o d’odo nla o
ishola tunde musiliu, ṣa maa wo wọn niran
ẹyin l’ọmọ adiye n tọ’ya ẹ, ko si ewu fun wa, rara
ẹnu wọn ni o pa wọn, babatunde, o da mi loju
ẹiyẹ orofo t’o bi’mọ meji, t’o nile oun ti kun ṣọ~ṣọ
asiko ti to ta o sọ fun wọn p’aṣiwaju yin la jẹ
ko ni buuru fun ori, k’ade fila s’orikun ẹsẹ
ko ni buuru fun ori, k’ade fila s’orikun ẹsẹ
ẹnu won mẹfa, ẹnu wọn meje
awa o b’ẹlẹnu meji ṣere mọ
[post~chorus]
ba’la o ni sọrọ, ọrọ a sọ’ra rẹ, to o ba n pe
wọn ṣi mi a tun le l’ẹẹnu de’bẹ, musiliu egungunjọbi
a a di jọ mi aa kọ’rin apala, tunde, iyẹn o difa
igberaga n ṣe wọn, babatunde haruna, mo n tẹnu mọ l’ojojumọ o
awọn da? wọn o da’dan mọ
awọn da? wọn o ni logo
didan ni yi o ma dan, iṣẹ oluwa, ẹyin ẹ ma tu wo
didan ni yi o ma dan, iṣẹ oluwa, ẹyin ẹ ma tu wo
yungba~yungba, l’aiye wa yi o ma dun o
[verse 2]
mo da duro na
kẹtẹkẹtẹ, bo ti ṣ’ọga alaru to
ko le gbe gẹdu ti o ba fẹ wọlẹ, ko ni jẹ ṣe’ru ẹ
aafi to ba fẹ f’ọrun jinfa, a l’oun bẹru mọto, sare lẹ~lẹ
ẹ jọwọ, e maa ṣ’ipe fun, n ṣe lo n d’ọgbọn ati rin o
ẹ jọwọ, e maa ṣ’ipe fun, n ṣe lo n d’ọgbọn ati rin o
isanwo alaṣọ mẹta, alaṣọ mẹta o~ay, alaṣọ
alaṣọ mẹta to n p’oni parọ, ko wa o
ba tunde
awọn t’emi complaini l’ojojumọ, musiliu mi, ishola o
wi pe tunde
wọn gbadun ẹ (wọn gbadun ẹ)
wọn jisoro (wọn jisoro)
wọn gbadun ẹ (wọn gbadun ẹ)
wọn jisoro (wọn jisoro)
wọn jisoro (wọn jisoro)
wọn jisoro (wọn jisoro)
[refrain]
tunde, ijo ti mo jo lana (kon below)
gbogbo ara lo n ro mi (kon below)
iya o gbọdọ gbọ (kon below)
baba o gbọdọ gbọ (kon below)
munsuru akinyẹmi (kon below)
kon, kon, kon below (kon below)
ọmọ akinyẹmi (kon below)
mọla haudu o (kon below)
aburo ọtunba (kon below)
akeem mi, adigun (kon below)
s’oko pa o (kon below)
ba mi ṣe itọju (kon below) titus babajide (kon below)
oppressor (kon below), awo major (kon below)
awo more blessing (kon below), gbogbo wọn pata (kon below)
kon below (kon below), oluṣọla (kon below)
ọmọ oyinloye (kon below), oyinbo onibatiri (kon below)
ni dosumu (kon below), ọrọ ni (kon below)
kon below (kon below)
[verse 3]
ẹ tun maa gbọ, ẹyin ẹlẹgbẹ, mo ni, “musiliu babatunde”
ishola babatunde, ka sọ fun wọn wipe
ẹ o gbọdọ o f’aja ma we maalu
ẹ o gbọdọ o f’aja ma we maalu
bo jẹ t’orin gidi, ishola ni ẹ ran ni sii
bo jẹ t’orin gidi, ishola ni ẹ ran ni sii
ba o ti ẹ laun sọ tan, k’ẹ mọ o
ba o ti ẹ laun sọ tan, k’ẹ mọ o
ba o ti ẹ laun sọ tan, k’ẹ mọ o
[outro]
b’aiye ba ti n yii, ishola, ka ma bawọn yii
ọpọn apala ti sun finally, o ti kuro ni t’atijọ
ishola tunde musiliu, ayin
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu yeat - föotjob addïction
- lirik lagu pokich - дождь за окном (rain outside)
- lirik lagu albert heijn - braadworsten met veel voordeel
- lirik lagu blehh - rockstar 101 (return of the mack)
- lirik lagu lil uzi vert - mission (looking at the stars)
- lirik lagu sixfthick - i work better in the dark
- lirik lagu gracia soberana música - nuestro dios
- lirik lagu svalgang - noctilume
- lirik lagu chloe hotline - days on victory parkway
- lirik lagu wizardjit - bawlin