lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu musiliu haruna ishola - ise oluwa ko seni toye

Loading...

[verse 1]
ìṣe olúwa ko s’ẹni tó ye, ìṣe olúwa ju t’alfa lo
ìṣe olúwa ko s’ẹni tó ye, ìṣe olúwa ju t’alfa lo
l’ọlọ́run ọba fi gbé wa ga
l’ọlọ́run ọba fi gbé wa ga o, le fi n binu, le fi pegan o

[verse 2]
musiliu babatunde
president fún àwọn al’apala kari naija pata~pata
b’a pe olórí, b’olórí n je
olórí kankan o gbọ́dọ̀ f’ohun torí pe, olórí ju olórí lo
b’a pe olórí, b’olórí n je
olórí kankan o gbọ́dọ̀ f’ohun torí pe, olórí ju olórí lo
musiliu ishola, l’asiwaju yín, ni bi ka kọrin apala to f’ọgbọ́n yo o
e lo meshi onu yín gbogbo yín o, e lo gb’ẹnu dake

[verse 3]
ba tunde ishola o, ọmọ egungun jobi
b’orin ba dùn, bi o dun, ẹni gbó wo lo mi a wi
àwa ní bàbà e yẹ ma ṣ’agídí
b’orin ba dùn, bi o dun, ẹni gbó wo lo mi a wi
àwa ní bàbà e yẹ ma ṣ’agídí
ka kọrin tó da, ishola ni asiwaju
orin tó f’ọgbọ́n yọ, ishola ni asiwaju
orin gidi, ishola ni asiwaju
musiliu, ọmọ egungun jobi


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...