lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu musiliu haruna ishola - eyin agba

Loading...

[intro]
mo ti wa ri b’aye kin to t’ile wa
mo ti ṣe’ba l’odo àwọn agba o
ẹyin agba, e je o tuwa ṣe

[chorus]
eyin agba o, o~ay
eyin agba t’e ba ri pe a ṣe yín
e ma ro’jo wa s’ibi t’o ṣoro ọmọ yin l’aje ogbon o de bi kan
ọmọ yin l’aje ogbon o de bi kan (ọmọ yin l’aje ogbon o de bi kan)
eyin agba o, o~ay
eyin agba t’e ba ri pe a ṣe yín
e ma ro’jo wa s’ibi t’o ṣoro ọmọ yin l’aje ogbon o de bi kan

[verse]
gatikule, gatikule
àti t’eba s’inu ṣáko maja, ogberi to ma je ma ni nkan
egunjobi ishola o, iyi t’oba olúwa fún e ko ni pare l’aye
e ṣ’amin kin gbó
egunjobi ishola o, iyi t’oba olúwa fún e ko ni pare l’aye
e ṣ’amin kin gbó
ọ̀tá kan bínú lásán, wọn o lè r’ana gbẹ gba, oba t’o ṣ’oni bo wa ṣ’ola
ao ni di ako bata l’àwùjọ olórin


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...