lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu king sunny ade - mo ri keke kan

Loading...

mo ri keke kan (kere ajalubale kere)
mo ri keke kan (kere ajalubale kere)
ko pobi pobi (kere ajalubale kere)

ko pobi pobi (kere ajalubale kere)
kori polobi (kere ajalubale kere)
ani mo ri keke kan (kere ajalubale kere)
mo ri keke kan o (kere ajalubale kere)
ko pobi pobi (kere ajalubale kere)
ko pobi pobi (kere ajalubale kere)
kori polobi o (kere ajalubale kere)

mo gbadura soke si baba aba o ke mi ma p’ofo
(mo gba, mo gbadura soke si baba o ke mi ma r’ofo)
mo gbadura soke si baba o ke mi ma p’ofo (mo gba, mo gbadura soke si baba o ke mi ma r’ofo)
omi ta gb’owuro pon ko j’elegbin o l’aye (baba j’aye mi o toro d’ale)
(baba, mama je n gbon se ku ó)
(baba mama je n f’ara gba’we, ki n r’owo fi lo’gba d’ojo ale mi o jo o ase)
ma s’owo ma j’ere (ma j’ere ohun ti mo ba f’owo mi se)
ma s’owo ma j’ere (ma j’ere ohun ti mo ba f’owo mi se)
sasa eda wo lo le s’ami adura yen
sasa eda wo lo le s’ami adura yen
amo nitemi mo s’ami adura mo gbe ito adura mi
mo sami adura mo gbe ito adura mi
ere l’omo oloja n je o to ba dale
ere l’obirin nje l’abo oja
ma j’ere, ma j’ere ohun ti mo ba f’owo mi se, ma j’ere o

ero ojo olowo (jalolo jalolo)
ero ojo olowo (jalolo jalolo)
e ba bami w’omomi o (jalolo jalolo)
e ba bami w’omomi (jalolo jalolo)
e si bami w’omomi o (jalolo jalolo)
oruko to momi mo n je (jalolo jalolo)
okan were were la n gbele oko
(wara wara ni di ọkọ mo niyi kekere oro omo niyi o dunmi yeye, jalolo jalolo)
ero ojo olowo (jalolo jalolo)
ero ojo olowo (jalolo jalolo)
e si bami r’omomi o (jalolo jalolo)
omo atata l’omoni (jalolo jalolo)
oruko to momi mo n je (jalolo jalolo)
okan were were la n gbele oko
(wara wara ni di ọkọ omo niyi kekere oro omo niyi o dunmi yeye jalolo jalolo)
ero oja olowo (jalolo jalolo)
(jalolo jalolo)
(jalolo jalolo)
ero oja olowo o (jalolo jalolo)
(jalolo jalolo)
ero oja olowo o (jalolo jalolo) (jalolo jalolo)
e si bami m’omo mi atata (jalolo jalolo)
oruko to mo mi mo n je (jalolo jalolo)


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...