lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu jaymikee - psalm 121

Loading...

èmi yóò gbé ojú mi
sórí òkè wọ̀n~ọn~nì
níbo ni ìrànlọ́wọ́ mi yóò ti wá

ìrànlọ́wọ́ mi tí ọwọ́ olúwa wá
ẹni tí ó dá ọ̀run, ayé
òun kì yóò jẹ́ kí ẹsẹ̀ rẹ kí ó yẹ̀;

ẹni tí ó pa ọ́ mọ́ kì í tòògbé
kíyèsi, ẹni tí ń pa israẹli mọ́
kì í sùn

olúwa ni olùpamọ́ rẹ;
olúwa ní òjìji rẹ
ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ
ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ

olúwa yóò pa ọ́ mọ́
kúrò nínú ibi gbogbo
olúwa yóò pa ọkàn rẹ mọ́

olúwa yóò pa àlọ
àti ààbọ̀ rẹ mọ́
láti ìgbà yìí lọ
àti títí láéláé
olúwa yóò pa àlọ
àti ààbọ̀ rẹ mọ́
láti ìgbà yìí lọ
àti títí láéláé

olúwa yóò pa àlọ
àti ààbọ̀ rẹ mọ́
láti ìgbà yìí lọ
àti títí láéláé

olúwa yóò pa àlọ
àti ààbọ̀ rẹ mọ́
láti ìgbà yìí lọ
àti títí láéláé


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...