
lirik lagu islambo - pocket 5
[intro]
oba alaṣakaṣa
o ma n daṣakaṣa
[chorus]
olúwa lo ko’la owo mi, ko fi pele si (oba mi oke)
mo n ga, mi o kere si (janla ja lailu)
ma ko kukere si
ma ra aṣo tuntun l’ojo keresi
mo n gbe wọn lo
mo n gbe wọn, mo n gbé wọn trabs
mon gbe wọn lo
gbe wọn de be mi o test drive
mo n gbé wọn lo
mo n gbe wọn, mo n gbé wọn trabs
mo n gbé wọn lo, mo ti sin’gbo si pocket 5
[verse 1]
ọmọ ol’ọdún ye’ra wo
na where gbadun dey me i go
mo gbe s’ori bi pineapple
igbadun ma n heal bi àgbò
h~llo story of a n~gga
ina lon lo keke elijah
na aura bi liver
dispatcher delivery
[interlude]
(who’s there?)
dispatcher
(oh sorry, i’m in the bathroom)
(drop it at the doorstep)
[verse 2]
o da pe e n vibe (no be only me dey feel am)
mo ri pe ooo gas (ponponpon bila)
shori mustache (herbert macur cur)
ori lo mo far (o lor far far)
i’m classic and wobey
tested and okay
crazy melody
kosi office like opay
fo sile, fo soke
they wonder where this boy dey see lamba like this
opo gan ni body
lamba to high ju canabis
if alisha no gree to kiss
i face my front malo muti
na why i dey road
opa o pejo
when your heart is so cold
correct your typo
activate your psycho, romance your bible
[chorus]
olúwa lo ko’la owo mi, ko fi pele si (oba mi oke)
mo n ga, mi o kere si (janla ja lailu)
ma ko kukere si
ma ra aṣo tuntun l’ojo keresi
mo n gbe wọn lo
mo n gbe wọn, mo n gbé wọn trabs
mon gbe won lo
gbe wọn de be mi o test drive
mo n gbé wọn lo
mo n gbe wọn, mo n gbé wọn trabs
mo n gbé wọn lo, mo ti sin’gbo si pocket 5
[outro]
[?]
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu 44ash - can't think rn
- lirik lagu destinezia - away
- lirik lagu guepardio - leopardo celeste
- lirik lagu omega - megbántottál
- lirik lagu muffin, filv & junona boys - la la la
- lirik lagu fpc kevin - dark knight 2
- lirik lagu malone (fra) - j'avance
- lirik lagu walrus (jpn) - seven
- lirik lagu street sects - entertainment law
- lirik lagu fchdatfoes - темный принц