
lirik lagu islambo - cook
[intro]
ha, hold something
(niphkeys)
oba aláṣàkaṣà
[verse 1]
the street is highly congested
àwa ma ri nkàn jẹ sẹ
wobey and tested
akínkanjú no be ben 10
wells fargo yàtọ sí kuda
bi hennessy ṣe yato si gulder
steady carrying ewé, i’m not carried away
hold something
[pre~chorus]
consolidate
eni ṣíṣe lon ṣo holiday
consoli~gbadun
akata lan basun
consoli~j~pon
malo gbe iyabo ni jákàndé
consolidate (haibo)
at the same time kos’holiday
[chorus]
let him cook (ṣe e ngbọ lamba yi?)
hear this dude (wa gbọ lamba yi)
let him cook (ṣe e ngbọ lamba yi?)
hear this dude (jọ wa gbọ lamba yi)
let him cook (ṣe e ngbọ lamba yi?)
hear this dude (abi ẹ gbọ lamba ni?)
let him cook (ṣе e ngbọ lamba yi?)
hear this dude
[verse 2]
my lamba is surplus
ẹ ma jasi, ẹ wa gbasi
i’m activе like thief
koto di pe won laju pa (koto di pe won laju pa)
o tidi baraku bai (o tidi baraku bai)
igbadun o si feni to ja
tan t’ọlọ́run ke hallelujah
ha, òdòdó lọ’wọ’, igbàyílolá
lamba ti o sin google (lamba ti o si n google)
jọ wo synagogue (jọ wọ synagogue)
abi ẹ nri double (ha, ya, ya)
kọlu ni o ni cuddle
[pre~chorus]
consolidate
eni ṣíṣe lon ṣọ holiday
consoli~gbadun
akata lan basun
consoli~j~pon
malo gbe iyabọ ni jákàndé
consolidate (haibo)
at the same time ko s’holiday
[chorus]
let him cook (ṣe e ngbọ lamba yi?)
hear this dude (wa gbọ lamba yi)
let him cook (ṣe e ngbọ lamba yi?)
hear this dude (jo wa gbọ lamba yi)
let him cook (ṣe e ngbọ lamba yi?)
hear this dude (abi ẹ gbọ lamba ni?)
let him cook (ṣe e ngbọ lamba yi?)
hear this dude (e wa gbọ lamba)
[outro]
talo lo panadol?
jo mama dull
ha, lamba po
jọ, jọ, jọ
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu interstellar cowboys - tramonto infernale
- lirik lagu s.3000 - hopfenoligarchen
- lirik lagu daddy issues - glue sniffer
- lirik lagu kesmeseker - en çok seni
- lirik lagu dina mirko - фокус
- lirik lagu newyyn - jdanse pas sur la piste :/
- lirik lagu the heels - happy after you
- lirik lagu aarlon - saavan - acoustic
- lirik lagu mirmoney - money flow
- lirik lagu werstany - worked (4:00 am)