lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu ibrahim maalouf & angélique kidjo - omije

Loading...

oba salomon, ojo ènin mon wa dobalè
dudu l’ara mi
émin ninkan bi omonde kekere
alafia, igberaga
kin’le wa ri yin, mon koja ojo irin ti ogun
dudu l’ara mi
n’tori eye goolu yin, lowa jishè
alafia, igberaga
ti awon eniyan ton fè alafia

omin wo lo doun, ti igbamin ma koro
omin to tèlé mi si ibikibi ti mon lo
igbami oman doun, igbami oman koro
igbi to tèlé mi si ibikibi ti mon lo
o kossi olori kan bi èmin towa ni afirika
ti koni nin iwariiri foun
agbara to ju agbara eyin oba salomon
kossi olori kan bi emin towa ni afirika
ti koni nin iwariiri foun
agbara to ju agbara eyin oba salomon

« omidjè, igbami ma doun, igbami ma koro
omidjè to tèlé mi l’opopona yin
omidjè, ma doun, igbami o ma koro
ominjè lo dja gba min l’onan yin. »

oba salomon, ojo ènin mon wa dobalè
dudu l’ara mi
émin ninkan bi omonde kekere
alafia, igberaga
kin’le wa ri yin, mon koja ojo irin ti ogun
dudu l’ara mi
n’tori eye goolu yin, lowa jishè
alafia, igberaga
ti awon eniyan ton fè alafia

omin wo lo doun, ti igbamin ma koro
omin to tèlé mi si ibikibi ti mon lo
igbami oman doun, igbami oman koro
igbi to tèlé mi si ibikibi ti mon lo
o kossi olori kan bi èmin towa ni afirika
ti koni nin iwariiri foun
agbara to ju agbara eyin oba salomon
kossi olori kan bi emin towa ni afirika
ti koni nin iwariiri foun
agbara to ju agbara eyin oba salomon

« omidjè, igbami ma doun, igbami ma koro
omidjè to tèlé mi l’opopona yin
omidjè ma doun, igbami o ma koro
ominjè lo dja gba min l’onan yin. »


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...