
lirik lagu ibrahim maalouf & angélique kidjo - ifé
oni iyawo ogota, ninou awon obinrin to lèwa gan
ati okpolokpo, ati okpolokpo
ma gbagbé awon ogori alè, tè nin
ati gbogbo awon tara ijoba rè
ati okpolokpo, makeda, makeda, makeda
ti won ni ikoko ifè foun yin
shugbon, lale yi mori ninu oju yin
ati okpolokpo, ati okpolokpo
kpé okan obinrin kan lo n’da yin l’odju !
ati okpolokpo , makeda
makeda, makeda eh !
kini n’kan, ta m’kpé nin imi
kossi, ko djè ifé
kini n’kan, ta m’kpé nin emi
kossi, ko lè djè ifé
eyi ti o tu kpalè kpelou agara a
okan ènin ti o ni sokan
kini^n’kan, ta m’kpé nin emi
kossi, ko lè djè ifé
ko lè djè ifé
elo dja yé yin, kpèlou igbadun kpikpo, kpikpo
makeda ati okpolokpo, ati okpolokpo
ti eniyan ko le foju mon
ati okpolokpo okan ibanuje
ati okpolokpo, makeda
ti won ni ikoko ifè foun yin
shugbon, lale yi mori ninu oju yin
ati okpolokpo, ati okpolokpo
kpé okan obinrin kan lo n’da yin l’odju !
ati okpolokpo , makeda
nin sinko èwa kodju mon min
nin sinko èwa kodju mon min
lesso m’kpé omi ti mon moun
omi aafin rè, emin mon ji nin
kini n’kan, ta m’kpé nin imi
« ife ti mou ni foun e ni, makeda »
kini n’kan, ta m’kpé nin èmi
« ife ti mou ni foun e ni, makeda »
kini n’kan, ta m’kpé nin imi
kossi, ko djè ifé
kini n’kan, ta m’kpé nin emi
kossi, ko lè djè ifé
eyi ti o tu kpalè kpelou agara a
okan ènin ti o ni sokan
kini n’kan, ta m’kpé nin imi
kossi, ko djè ifé
kini n’kan, ta m’kpé nin emi
kossi, ko lè djè ifé
eyi ti o tu kpalè kpelou agara a
okan ènin ti o ni sokan
kini n’kan, ta m’kpé nin imi
kossi, ko djè ifé
kini n’kan, ta m’kpé nin emi
kossi, ko lè djè ifé
eyi ti o tu kpalè kpelou agara a
okan ènin ti o ni sokan
kini n’kan, ta m’kpé nin imi
kossi, ko djè ifé
kini n’kan, ta m’kpé nin emi
kossi, ko lè djè ifé
eyi ti o tu kpalè kpelou agara a
okan ènin ti o ni sokan
kini^n’kan, ta m’kpé nin emi
kossi, ko lè djè ifé
ko lè djè ifé
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu voldy moyo - sinning
- lirik lagu yta apollo - waste of time
- lirik lagu asleep in the sea - cancer and bones
- lirik lagu yokai jaki - mass damage
- lirik lagu svir - kmb
- lirik lagu devito - koka (live)
- lirik lagu only the poets - forget your name
- lirik lagu jonas blue & max - naked (nathan dawe remix)
- lirik lagu russ - finally rich
- lirik lagu neffex - they call me a god