lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu ibrahim maalouf & angélique kidjo - alikama

Loading...

èmi makeda, ti a toun ma m’kpè ni balkis
èmi ni ayaba ti awọn guusu
èmi makeda, ti a toun ma m’kpè ni balkis
èmi ni ayaba ti awọn guusu

o fi mi, o fi mi tché èlèwon ti è
o fi mi, o fi mi tché èlèwon ti è
olọgbọn ti ọlọgbọn èyin solomoni
eyin l’oba jerusalemu

èmi makeda, ti a toun ma m’kpè ni balkis
èmi ni ayaba ti awọn guusu
èmi makeda, ti a toun ma m’kpè ni balkis
èmi ni ayaba ti awọn guusu

o fi mi, o fi mi tché èlèwon ti è
o fi mi, o fi mi tché èlèwon ti è
olọgbọn ti ọlọgbọn èyin solomoni
eyin l’oba jerusalemu

èmi makeda, ti a toun ma m’kpè ni balkis
èmi ni ayaba ti awọn guusu
èmi makeda, ti a toun ma m’kpè ni balkis
èmi ni ayaba ti awọn guusu

èmi mo fẹ lati lọ si ile mi
èmi mo fẹ lati lọ si ile mi
olọgbọn ti ọlọgbọn èyin solomoni
eyin l’oba jerusalemu

ah ah ah
ah ah ah
ah ah aaaah

bè enin awọn onidajọ
won dadjo mi l’oòrùn
emin ole lo ilé mi mon
bè enin awọn onidajọ
won dadjo mi l’oòrùn
emin ole lo ilé mi mon
ki ni won ma jin si lè ninu òkunkun
shugbon o si wa l’ayé!
igbami oma parun ninoun ofo
lèè kan nan ni ayé man kpada wa

ki ni won ma jin si lè ninu òkunkun
shugbon o si wa l’ayé!
igbami oma parun ninoun ofo
lèè kan nan ni ayé man kpada wa

ki ni won ma jin si lè ninu òkunkun
shugbon o si wa l’ayé!
igbami oma parun ninoun ofo
lèè kan nan ni ayé man kpada wa


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...