lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu hurricane lfnd fln - rumbo

Loading...

àwa méjeèje o
a lọ léè wòran o
òjò ló pa wá bọ’
a ya ilé arúgbó
arúgbó se kókò mi ó jẹ
ìyàwó sebẹ’ o

lálá tó rélulẹ’
òkè lò n bọ’ o
motí n sáré látígbà kékeré mi o
mi ò mọhun tó dé o
bí a kóbá rẹ’ni gbọ’kànlé o
àá tẹra mo iṣé ẹni
bó pẹ’ẹ bó yáá o
oríì mi áá dire

rumbo rumbo
àsìkò n̄lọ but máá sáré o
rumbo rumbo
i no wan run but time no dey o
rumbo rumbo
ọkùnrin ni mí mo máá tó rádé o
rumbo rumbo rumbo
ẹ’mí nbẹ ìrètí nbẹ

adánitódáyé o
ìgbàwo ìgbàwo ìgbàwo ni?
ọsà ti fẹ’ wẹ’mí jákè
jákè!
adánitódáyé o
ìgbàwo ìgbàwo ìgbàwo ni?
ọsà ti fẹ’ wẹ’mí jákè
jákè!

ìbá jẹ’pé iṣẹ’ lọ’fin ṣeè o
apá mi méjéèjì yóò dádé o
ka ṣiṣé bí ẹrú ò da nnkan o
àlùbáríkà ló jù
oríì mi àfire, àfire orí á gbó
orí gbágíri gbemì gbemi
oríì mi áá dire

rumbo rumbo
àsìkò n̄lọ but máá sáré o
rumbo rumbo
i no wan run but time no dey o
rumbo rumbo
ọkùnrin ni mí mo máá tó rádé o
rumbo rumbo rumbo
ẹ’mí nbẹ ìrètí nbẹ


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...