lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu hibeekay - iranlowo

Loading...

#verse
oluwa ni imole mi
ati igbala mi tani emi yo beru
agbara emi mi
aya tani yo fo mi
okan mi bale
tori mori oluwa ti mo gbojule
oun ni yio gbemileke
tori mi o le da se
lai si iranlowo re
oluwa iwo ni
mo gbe okan mi
soke si o olorun mi
ma je koju ko ti mi
baba mo duro ti o
baba fona re han mi
ki o si ko mi
kin le je eso anu re
toripe kosi ona miran
lati se yege
lai si iranlowo re

#chorus
iranlowo
(ehh) ibukun oluwa lo n mu ni la
(itoju o) itoju oluwa lo n wo ni san
(itoni o) itoni oluwa lo n mu ni gbon
(ehh baba ran mi lowo) baba ran mi lowo
(jesu oluwa) jesu oluwa lowo soro mi
(nitoriwipe) owo re ma lo n gbe ni ro
anu re lo n mu ni sogo
baba ran mi lowo
#verse
emi yo gboju mi sori oke wonni
nibo iranlowo mi yio ti wa
iranlowo mi yio towo oluwa wa
ti o da orun oun aye
oba ayeraye
oun ki yo je ki ese mi ko ye
nitori oun ni olupamo mi
mo se ni
alewilesе
aleselewi
baba awimayеhum
ni mo se so wipe se
oluwa iwo ni
mo gbe okan mi
soke si o olorun mi
ma je koju ko ti mi
baba mo duro ti o
baba fona re han mi
ki o si ko mi
kin le je eso anu re
toripe kosi ona miran
lati se yege
lai si iranlowo re

#chorus
(sing iranlowo se) iranlowo
(ibukun oluwa) ibukun oluwa lo n mu ni la
(itoju oluwa) itoju oluwa lo n wo ni san
(itoni oluwa) itoni oluwa lo n mu ni gbon
(baba ran mi lowo) baba ran mi lowo
(jesu oluwa) jesu oluwa lowo soro mi
(nitoriwipe) owo re ma lo n gbe ni ro
anu re lo n mu ni sogo
baba ran mi lowo
#bridge
ni mo se so wipe se
iranlowo
ase oluwa lo n gbe ni leke
oro oluwa lo n gba ni la
abo oluwa lo n pa ni mo
baba ran mi lowo
jesu oluwa da si oro mi
tori, idasi re ma n niyanju
ohun lo n fun mi ni idunu
baba ran mi lowo
ni mo se so pe
oro re lo n gba ni la
anu re lo n mu ni sogo
(baba ran mi lowo)
ibukun re lo n mu ni la
owo re lo n mu ni ro
(baba ran mi lowo)
itoju re lo n wo ni san
itoni re lo n mu ni gbon
(baba ran mi lowo)
oya sing iranlowo se

#chorus
iranlowo
ibukun oluwa lo n mu ni la
itoju oluwa lo n wo ni san
itoni oluwa lo n mu ni gbon
baba ran mi lowo
jesu oluwa lowo soro mi
owo re ma lo n gbe ni ro
anu re lo n mu ni sogo
baba ran mi lowo


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...