lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu hibeekay - agogo ati shekere

Loading...

#chorus
efi duru korin si oluwa oba mimo
f’ipe ohun fere yin oluwa olorun wa
k’agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
eho iho ayo si oluwa nigba gbogbo
efi duru korin si oluwa oba mimo
f’ipe ohun fere yin oluwa olorun wa
k’agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
eho iho ayo si oluwa nigba gbogbo

#instrumental

#verse
e korin titun s’oluwa
nitori to ti se ohun iyanu
jeki okun ko ma ho pelu ikun re
je ki odo ko ma sape k’oke ma sajoyo
e fope f’oluwa (o seun)
anu re duro lailai (o seun)
o fi ogbon da orun (o seun)
o te ile lori omi (o seun)
o da awon imole nla (o seun)
orun lati joba osan (o seun)
osupa ati irawo joba oru (o seun)
e ba mi f’ope f’olorun ehh
#chorus
efi duru korin si oluwa oba mimo
f’ipe ohun fere yin oluwa olorun wa
k’agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
eho iho ayo si oluwa nigba gbogbo
efi duru korin si oluwa oba mimo
f’ipe ohun fere yin oluwa olorun wa
k’agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
eho iho ayo si oluwa nigba gbogbo

#verse
moniwipe
e lo si enu ona re teyin tope
ati si agbala re teyin tiyin
e dupe e f’ibukun fun oruko re
nitori to po lore anu re konipekun
eniti o ranti wa (o seun)
ninu iwa irele wa (o seun)
anu re duro lailai (o seun)
o da wa nde lowo ota (o seun)
o fi ounje fun gbogbo eda (o seun)
o sise iyanu nla (o seun)
jeki gbogbo ohun to lemi (o seun)
ko fiyin f’oluwa oba awon oba

#chorus
efi duru korin si oluwa oba mimo
f’ipe ohun fere yin oluwa olorun wa
k’agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
eho iho ayo si oluwa nigba gbogbo
efi duru korin si oluwa oba mimo
f’ipe ohun fere yin oluwa olorun wa
k’agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
eho iho ayo si oluwa nigba gbogbo
#instrumental

#chorus
efi duru korin si oluwa oba mimo
f’ipe ohun fere yin oluwa olorun wa
k’agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
eho iho ayo si oluwa nigba gbogbo
efi duru korin si oluwa oba mimo
f’ipe ohun fere yin oluwa olorun wa
k’agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
eho iho ayo si oluwa nigba gbogbo
eho iho ayo si oluwa nigba gbogbo
eho iho ayo si oluwa nigba gbogbo
eho iho ayo si oluwa nigba gbogbo
eho iho ayo si oluwa nigba gbogbo


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...