lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu hadassah vincent barucabamusic global network - as long as i live

Loading...

eledumare oba ogo
awimayehun alagbara
eledumare oba ogo
awimayehun alagbara

alagbada ina atobiju ologojulo
akpata ayeraye oyigiyigi onimajemu
atogbojule atunorise arugbo ojo
olorun agbalagba
ma fun nwo logo, ogo, ogo

ma sawa fun iran lowo
eda mi lohun pelu ina
eja sheke sheke mi
lowo ota mi
ma sawa fun iran lowo
eda mi lohun pelu ina
eja sheke sheke mi
lowo ota mi

ma sawa fun iran lowo
ma sawa fun iran lowo eh
ma sawa fun iran lowo
ma sawa fun iran lowo
ma sawa fun iran lowo
ma sawa fun iran lowo eh
ma sawa fun iran lowo
ma sawa fun iran lowo
as long as i live i’ll give you praise
as long as i live i’ll worship you
as long as i live i’ll dance for you
as long as i live i’ll bow before your throne

eledumare, oba titi lai lai
eledumare, oba awon oba
eledumare, oba titi lai lai
eledumare, oba mimo mimo mimo

eledumarе oba ogo awimayehun alagbara
eledumare oba ogo awimayеhun alagbara

ma sawa fun iran lowo
ma sawa fun iran lowo eh
ma sawa fun iran lowo
ma sawa fun iran lowo
ma sawa fun iran lowo
ma sawa fun iran lowo eh
ma sawa fun iran lowo
ma sawa fun iran lowo

as long as i live i’ll give you praise
as long as i live i’ll worship you
as long as i live i’ll dance for you
as long as i live i’ll bow before your throne
eledumare, oba titi lai lai
eledumare, oba awon oba
eledumare, oba titi lai lai
eledumare, oba mimo mimo mimo
eledumare, oba titi lai lai
eledumare, oba awon oba
eledumare, oba titi lai lai
eledumare, oba mimo mimo mimo

great, baba aye, great, baba aye
great, baba aye, great, baba aye


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...