lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu göke - baba

Loading...

baba o o o o
baba o o o o
baba o o o o
mo wa juba re

olorun ana olorun oni
olorun aiyeraiye
ese toju eranko ese toju eye
ese toju aya ese toju oko
ese toju omo ese toju gbogbo eda
baba ton gbadura
baba ton dabira
baba tongba ni, baba ton yo ni

baba o o o o
baba o o o o
baba o o o o
mo wa juba re
baba o o o o
baba o o o o
baba o o o o
mo wa juba re
baba o o o o
baba o o o o
baba o o o o
mo wa juba re

olorun ife, olorun ogo
olorun ife, olorun ogo
olorun ododo
olorun anu, olore mi
oludarijini, oloore-ofe
olorun anu, oloore mi
olorun alaafia

baba ton gbadura
baba ton dabira
baba tongba ni, baba ton yo ni

baba o o, baba
baba o o, baba
baba o o, baba
mo wa juba re
baba o o o o
baba o o o o
baba o o o o
mo wa juba re
baba o o o o
baba o o o o
baba o o o o
mo wa juba re

emi ni baba, baba abba father mi
emi ni baba, baba ton gbadura mi
emi ni baba, ko si beru o
emi ni baba, ko ma si foya mo

ani mo ni baba, ife re lo somi domo
emi ni baba, oore ofe re lo gbamila
emi ni baba, ko si beru o
owo otun re baba ma lo gbe mi ro

enyin ni baba to to baba
enyin ni baba to ju baba lo

enyin ni baba to to baba
enyin ni baba to ju baba lo

enyin ni baba to to baba
enyin ni baba to ju baba lo

emi ni baba, baba, baba
emi ni baba, baba aiyeraiye
emi ni baba, baba, baba
emi ni baba, baba aiyeraiye
emi ni baba, baba, baba
emi ni baba, baba aiyeraiye


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...