lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu gbenga akinfenwa feat. olayiwola jagun - iba (feat. olayiwola jagun)

Loading...

morábábà, morábábà
eledumare ooo
to to ola re ba

iba, iba fun o ooo
toto ola re iba

awon angeli won f′ori bale
to to ola re ba
iba, iba fun o ooo
toto ola re iba

morababa, morababa
olutoju eniyan
to to ola re ba
iba, iba fun o ooo
toto ola re iba

call & resp

iba akoda aye oo, iba
iba aseda orun oo, iba
ato to gboju le, iba
ato to farati, iba
ato to feyin ti, iba
ato f’ise ogun ran, iba
asiwaju ogun lalo, iba
akeyin ogun labo, iba
oranmonise fayati, iba
oranmonise pon′mo seyin, iba
awo igba’run ma gbeje, iba
awo igba’run ma gbeje ooo, iba
olowo pin′re pin′re, iba
olowo ro’bi ro′bi, iba
o pin’re, pin′re kanmi ooo, iba
o pin’re, pin′re kan e ooo, iba

iba, iba, iba, iba
iba, iba, iba, iba
iba, iba, iba, iba

diving eulogy

morababa, morababa
eledumare ooo
to to ola re ba
iba, iba fun o ooo
toto ola re iba


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...