lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu fummi aragbaye - motini jesu lore

Loading...

1. mo ti ni jesu l‘ore, o j‘ohun gbogbo fun mi;

oun nikan l‘arewa ti okan mi fe

oun n‘itanna ipado, on ni enikan na

t‘o le we mi nu kuro n‘nu ese mi

olutunu mi l‘o je n‘nu gbogbo wahala

oun ni ki n k‘aniyan mi l‘oun lori

oun ni itanna ipado, irawp owuro

oun nikan l‘arewa ti okan mi fe

olutunu mi l‘o je, n‘nu gbogbo wahala

oun ni ki nk‘aniyan mi l‘on lori;

oun ni itanna ipado, irawo owuro

oun nikan l‘arewa ti okan mi fe

2. o gbe gbogbo ‘banuje at‘irora mi ru
o j‘odi agbara mi n‘igba ‘danwo;

‘tori re mo k‘ohun gbogbo ti mo ti fe sile

o si f’agbara re gbe okan mi ro;

bi aye tile ko mi, ti satani dan mi wo

jesu yo mu mi d‘opin irin mi;

oun ni itanna ipado, irawo owuro

oun nikan l‘arewa ti okan mi fe

3. oun ki y‘o fi mi sile, be k‘y‘o ko mi nihin

niwon ti nba fi ‘gbagbo p‘afin re mo;

o j‘odi ‘na yi ma ka, n ki y‘o berukeru

y‘o fi manna re b‘okan mi t‘ebi npa

‘gba mba d‘ade n‘ikeyin, uno r‘oju ‘bukun re

ti adun re y‘o ma san titi lae
oun ni itanna ipado, irawo owuro

oun nikan l‘arewa ti okan mi fe

amin

lyrics submitted by awowoye mosunmola funmilola


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...