lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu eazybie - ogo (glory)

Loading...

ogo (glory) x opakan
acapella..(chorus)
omo olu ijo mimo ni mi
sensen buri malaika
ti mo ti gbe emi mimo (oh)
jeki aye mi ko ni tunmo

(intro)
huuuh uhuuu huu
easyb ma re
oladimeji na my name opakan

(chorus)

omo olu ijo mimo ni mi
sensen buri malaika
ti mo ti gbe emi mimo (oh)
je ki aye mi ko ni tunmo (2x)

(verse 1)

omo olujo mimo
ologo mimo
ti moti gbe emi mimo
ti ati gbe emi mimo
gbogbo wa ti gbe emi mimo (oh)
eli elija (backup)eli elija
eli elija (ah ah)
orun si lekun malaika so ka lewa
(backup)eli elija
(chorus 2)

omo olu ijo mimo ni mi
sensen buri malaika
ti mo ti gbe emi mimo (oh)
je ki aye mi ko ni tunmo (2x)

(pre chorus)
keyboardist (respond)

malaika kabi ka la
yarobi rebi ka la (2x)

arire mako oladimeji na my name opakan

(verse 2)

gbogbo ohun to gbo mi je
loju mi lo dun ti o ko ja
olorun oba dakun fi mu aye mi dara
ebe ni mo be ó ôlorun oba
dakun answer my prayer
nkan ogbudo se omo ôlorun
nkan ogbudo se omo ôlorun
nkan ogbudo se omo ôlorun
nkan ogbudo se omo ôlorun
hun ko ni olorun ni bo mi ran
iwo nikan ni mo di ro mo
si be si be mo un dupe
si be si be aye ope yo
(chorus)

omo olu ijo mimo ni mi
sensen buri malaika
ti mo ti gbe emi mimo (oh)
je ki aye mi ko ni tunmo (2x)

(pre chorus)

malaika kabi ka la
yarobi rebi ka la (2x)

(outro)

omo olu ijo mimo ni mi
sensen buri malaika
ti mo ti gbe emi mimo oh
je ki aye mi ko ni tunmo


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...