lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu eazy mighty - hallelujah 2.0

Loading...

yeh yeh
eazy mighty
eazy mighty yeh eh

hallelujah si ogun orun
hallelujah si ogun orun
ebami ke hallelujah
hallelujah si ogun orun
hallelujah si ogun orun
ebami ke hallelujah
yeh, olorun moses orimolade
emi re motuntiwa mowaso wipe ose yeh
iwo mo gbojule iwo mo feyin ti, ota wade won bere bawo ni mosese
emi seba olorun agbotijesu emi ni oo leyin, nitorina emi o le sa f′esu
emi ti seba olorun adeola
asakiatu asadiawa moti wa o wa, jeki ire mi wa
iwo ati ila orun gusu ati ariwa
yeh, lati ibere odun wa mio ku, mio s’aisan
mio gbomo sin, mio gb′aya sin, mio gb’oko sin
mowa dupe motuntiwa tun ope da
lati ibere odun wa mio ku, mio s’aisan
mio gbomo sin, mio gb′aya sin, mio gb′oko sin
mowa dupe motuntiwa tun ope da
hallelujah si ogun orun
hallelujah si ogun orun
ebami ke hallelujah
hallelujah si ogun orun
hallelujah si ogun orun
ebami ke hallelujah
hallelujah si ogun orun
hallelujah si ogun orun
ebami ke hallelujah
hallelujah si ogun orun
hallelujah si ogun orun
ebami ke hallelujah
momo riri ore
emi wa dupe mowa dupe lowo babaloke
momo riri ore~ eh~ eh
emi wa dupe mowa dupe lowo babaloke
baba mi ose
oje komo araye bami ke
baba mi se
gbemiga jekin le leke jekin le leke (yeh jekin le leke
lati ibere odun wa mio ku, mio s’aisan
mio gbomo sin, mio gb′aya sin, mio gb’oko sin
mowa dupe motuntiwa tun ope da
lati ibere odun wa mio ku, mio s′aisan
mio gbomo sin, mio gb’aya sin, mio gb′oko sin
mowa dupe motuntiwa tun ope da
hallelujah si ogun orun
hallelujah si ogun orun
ebami ke hallelujah
hallelujah si ogun orun
hallelujah si ogun orun
ebami ke hallelujah
hallelujah si ogun orun
hallelujah si ogun orun
ebami ke hallelujah
hallelujah si ogun orun
hallelujah si ogun orun
ebami ke hallelujah


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...