lirik lagu dj suru - beat
ebba ebba sùrù_baba iwa re ooo
me aladji mi o kewu
this true life story
gba ko gbòran
bèmbèrèkè idi rè
lo mu pastor yó ni churche
ma wa churche mon ooh
bèmbèrèkè idi rè lo da gobe
lè ni mosque
ma wa mosque mo ooh
bèmbèrèkè idi rè
adugbo wa lo ngbe
shade the first lady
o şe èyin bi taya
katapillar daddy wa
lati kékékéré lo npara
èni gba shade l òwò mi ma pa
ni awon boys npariwo
shade gba òkò l òwò mi ma pa
ni awon girls npariwo
eşu ni agbara ko ni gbala
shade wò churche è wo idi nla
emon ré ko wò pata
lecturer oo le kawé mon
pastor wa yò şubu
olouşò kilodé?
kilodé ti è şubu?
oni èlèran ara ni mi
ara oki nsé okuta
man jè nşè s olouwa
sister shade è bò si ita
odi djimaan, shade mura mosque
irunmonlè to nka couran
odé tayi dé bè
gobé ti nšèlè l òwò
alfa nwo idi shade(awo ja tò)
hadja ngbà hadji l oju(nitori shade)
leimanmu nwo bèmbèrèkè (awo şubu)
èni toyè ko pe irun
ègbò nti owi
aah aaah èwa wo bèmbèrèkèèèè ni m-ssal-ssi
this na gobé, gobé by shade
everywhere she day p-ss
lori streets won nwòlé kan lè
shade aah? you cover well your phones but why not your body
daddy-mummy sò ko gbò
ooo şemi l aanu(na pity thing)
sister shade ni bo lè badé
ko gbogu l aarun tè gbewalé
everything she puts ko de lè ri
na sanké sanké
to ba béré òla ju lo dé
everybody know say shade get bèmbèrè
but ewoni ka man wò şokoto wolé onilé
ooo şemi l aanu(na pity thing)
sister shade ni bo lè badé
ko gbogu l aarun tè gbewalé
bèmbèrèkèyin tibè tibè oti bèbèbè
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu be under arms - the long walk
- lirik lagu for the win - i won't let you go
- lirik lagu better life - ya same' el sallah
- lirik lagu associação atitude consciente - filhos do brasil
- lirik lagu spændt op squad - trappestjerne
- lirik lagu bucket hat mafia - we the shit
- lirik lagu nusky - aux souvenirs oubliés
- lirik lagu star cast - i can be
- lirik lagu venerea - raising my game
- lirik lagu i61 - ranger