lirik lagu congress musicfactory - se orúko re logo
Loading...
se orúko re logo
[akorin 1]
oluwa af’ogo fun oruko re
oluwa af’ogo fun oruko re
a fun yin logo ati owo
a juba a yin yin
a f’ogo fun oruko re
[akorin 2]
nisokan a yi itere ka
a gbe yin s’oke a tun gbe yin ga
alagbara ati oba
e joba t-tilai
a f’ogo fun oruko re
[akorin 1]
oluwa af’ogo fun oruko re
oluwa af’ogo fun oruko re
a fun yin logo ati owo
a juba a yin yin
a f’ogo fun oruko re
[akorin 2]
nisokan a yi itere ka
a gbe yin s’oke a tun gbe yin ga
alagbara ati oba
e joba t-tilai
a f’ogo fun oruko re
[ipari]
alagbara ati oba
e joba t-tilai
a f’ogo fun oruko re
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu celeste (band) - mais quel plaisir de voir cette tête d'enfant rougir et suer
- lirik lagu lorenzo fragola - good riddance (time of your life)
- lirik lagu regina - day by day - ghosts radio edit
- lirik lagu sam mackey - stuck in self-pity
- lirik lagu klub des loosers - roulette russe
- lirik lagu sarah geronimo - ikaw ang aking pangarap
- lirik lagu stunnah - du bist ...
- lirik lagu brusco - fino all'alba
- lirik lagu muddy waters - country blues no. 1
- lirik lagu alligatoah - dagegen