lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu congress musicfactory - mímó ni òdó àgùtan

Loading...

mímó ni òdó àgùtan

[akorin}
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa

[akorin]
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa

[ẹsẹ 1]
gbogbo eda f’ogo fun o
gbogbo okan wa bukun f’oruko re
ede, eya ati awon orile ede
eniyan mimo nkorin iyin re

[akorin]
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa

[ẹsẹ 2]
a teriba nibi mimo re
a gbowo s’oke a juba re
oluwa eyin nikan l’owo yi ye
iwo nikan ni gbogbo iyin ye
gbogbo iyin

[akorin]
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa

[ipari]
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa to tun nbo waaaa


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...