lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu brymo - adedotun

Loading...

verse 1
awon adan fo loke
wan foka si oju orun
wan o ma mo ibi won lo
eledua lo n shey ike won
ko keyin si é oré o
o wun o n wa
o wa ni waju re

hook
adedotun…….
oyindamola mi…….
ero gbogbo e ba gberin
adedotun o………….

verse 2
awon adan fo loke
ni igba igba
won ku oju orun
won o ma mo iwun wan n je
eledua lo n sho wan
lo n bo wan
ko pamo si é
oré ooooooo
o wa lo sokoto
o wa lapo sokoto

hook
adedotun…….
oyindamola mi…….
ero gbogbo e ba gberin
adedotun o………….
(x2)

ko pamo si é
oré o
owun o n wa
o wa ni waju re
ore o……..


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...