lirik lagu bhadboi oml - owereke
chorus
ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
ówéréké mó tun gbé dódé (ówéréké)
eh, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
ashé ólórun ló rán mi wá (ówéréké)
ó rán mi si mushin, losi ibadan (ówéréké)
ó rán mi si ilé~ife, yá lóshódi (ówéréké)
chorus
éwó ni ká shóré tán, káá de di hod (ówéréké)
káá shóré tán, káá de tun lóshó tii (ówéréké)
eh, ówéréké, igbayi lówó (ówéréké)
eh, ówéréké, igbayi lolá (ówéréké)
ówéréké, igbayi tójó ro (ówéréké)
igunnugun mi óde ni ku n léwé (ówéréké)
akalamagbó óni ku lósu mo oo (ówéréké)
eh, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
ah, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
chorus
ówéréké, mó tun gbé dódé (ówéréké)
ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
eh, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
ówéréké, kósi pressure seh (ówéréké)
ówéréké, kóni si werey mo oo (ówéréké)
ah, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
ówéréké, mó tun gbé dódé (ówéréké)
ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
verse
ah, kilá mu wáye, ayé lá má fii silé si
tó difa fun eni tó bi mo, tó lo ji resi
oga go collect your two portion, kon fi die sii
igbaju, igbamu pupo, ni ti keri, keri
iyawó enikan, asho mu enikán
enikán ó binu enikán
enikán ó dun bu enikán
iyawo temi, asho mu elómi
toba gbowo e ló mi, a tun wa ji ówó temi
chorus
ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
ówéréké, mó tun gbé dódé (ówéréké)
eh, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
ashé ólórun ló rán mi wá (ówéréké)
ó rán mi si mushin, losi ibadan (ówéréké)
ó rán mi si ilé ifę, yá lóshódi (ówéréké)
chorus
éwó ni ká shóré tán, káá de di hod (ówéréké)
káá shóré tán, káá de tun lóshó tí (ówéréké)
eh, ówéréké, igbayi lówó (ówéréké)
eh, ówéréké, igbayi lolá (ówéréké)
ówéréké, igbayi tójó ro (ówéréké)
igunnugun mi óde ni ku n léwé (ówéréké)
akalamagbó óni ku lósu mo oo (ówéréké)
eh, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
ah, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
chorus
ówéréké, mó tun gbé dódé (ówéréké)
ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
eh, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
ówéréké, kósi pressure seh (ówéréké)
ówéréké, kóni si werey mo oo (ówéréké)
ah, ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
ówéréké, mó tun gbé dódé (ówéréké)
ówéréké, ówéréké oh (ówéréké)
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu louie ray - spot action
- lirik lagu deshaunjay - victory lap
- lirik lagu negga - você, seu type - remix
- lirik lagu london after midnight - scary monsters
- lirik lagu oxamyt & heavenvoice - fntzy club
- lirik lagu darwin miller - lml
- lirik lagu zak p - antivax moms - demo
- lirik lagu interstellar cowboys - roberto fai la cacca
- lirik lagu matt draugos & klwn cat - commercial interruption! (tesla surge)
- lirik lagu starflyer 59 - yz80