lirik lagu beautiful nubia and the roots renaissance band - moworesire
“onítibí yẹn nlọ, ó mà ṣe bẹbẹ
wọ′n l’óun t′ó ti gbé ṣe, ó mà tóbi o
l’ọ’jọ′ ọjọ′ yẹn, ó ṣe kísà, ó ná’wó ná′ra
ọ’nà rèé, kálọ ká fi hàn ọ′”
la’jú rẹ sílẹ′ ko r’ẹ’yìn atanijẹ
la′tí rẹ sílẹ′, ko gbọ”rọ’ òtítọ′ nì
ẹni nṣ’ọdún owó yẹn, ṣ′ó l’áyọ′ nínú?
gbogbo oun tó ndán kọ’ ni wúrà o
jọ’wọ′ m′ọ’wọ′ rẹ sí’re ọ′rẹ’, ṣè′wọ’n t’ápá rẹ bá ká àbúrò
má ṣe wù′wà ìbàjẹ′, má ṣe k’ẹ′gbẹ’ ọlọ′tẹ’
ọ′nà tóró yẹn ló l’ádùn gan
jọ’wọ′ m′ọ’wọ′ rẹ sí’re ọ′rẹ’, ṣè′wọ’n t’ápá rẹ bá ká àbúrò
má ṣe mọ′dàrú, má ṣe k′ẹ’gbẹ′ ọlọ’bùn
ìwà rere yẹn ní f′ọkàn ẹni ba’lẹ′
àgbà sọ fún wa ní’gbà ọ’dọ′ o, ẹni ire
wọ′n ló yẹ k’ọ′mọlúàbí ní ìtẹ’lọ′rùn
ká má fì ‘ka mẹ′wà’ jẹun lẹ’ẹ′kan t′àìgbọ’n kọ′ ni ká ṣe pẹ’lẹ′
ẹni l’ọ′lá ìyẹn á mà bá’lẹ’ lọ
ẹni ò ní kò ní kọjá ọjọ′ tirẹ′
ká má ṣe bí ọlọ’rọ′ tó gbàgbé ọgbọ’n
ìwa tó dára ló ga jù o
jọ′wọ’ m′ọ’wọ’ rẹ sí′re ọ′rẹ’, ṣè′wọ’n t′ápá rẹ bá ká àbúrò
má ṣe wù’wà ìbàjẹ′, má ṣe k’ẹ’gbẹ′ ọlọ′tẹ’
ọ′nà tóró yẹn ló l’ádùn gan
jọ′wọ’ m′ọ’wọ’ rẹ sí′re ọ′rẹ’, ṣè′wọ’n t′ápá rẹ bá ká àbúrò
má ṣe mọ’dàrú, má ṣe k′ẹ’gbẹ’ ọlọ′bùn
ìwà rere yẹn ní f′ọkàn ẹni ba’lẹ′
m’ọ′wọ’ rẹ sí′re ọ’rẹ’, ṣè′wọ′n t’ápá rẹ bá ká àbúrò
má ṣe wù′wà ìbàjẹ’, má ṣe k′ẹ’gbẹ′ ọlọ’tẹ’
ọ′nà tóró yẹn ló l′ádùn gan
jọ’wọ′ m’ọ′wọ’ rẹ sí′re ọ’rẹ’, ṣè′wọ′n t’ápá rẹ bá ká àbúrò
má ṣe mọ′dàrú, má ṣe k’ẹ′gbẹ’ ọlọ′bùn
ìwà rere yẹn ní f’ọkàn ẹni ba’lẹ′
onítibí yẹn nlọ, ó mà ṣe bẹbẹ
ah, onítibí yẹn nlọ, ó mà ṣe rere
ah, onítibí yẹn nlọ, ó mà ṣe bebe
onítibí yẹn nlọ, ó mà ṣe dada
onítibí yẹn nlọ, ó mà ṣe bebe
onítibí yẹn nlọ, ó mà ṣe rere
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu offsite - creator
- lirik lagu juli - wenn das alles ist
- lirik lagu lavan abhishek & kamani lasanthika - hadakari
- lirik lagu ivete sangalo - acalme sua alma
- lirik lagu brycen chaisson - static blast
- lirik lagu tkun - vega
- lirik lagu ukeboy - ćmy
- lirik lagu lil soda boi - what does it all mean
- lirik lagu flagras - toverie
- lirik lagu walg - help ons niet