lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu beautiful nubia and the roots renaissance band - ireti-ogo

Loading...

ẹni t′ó dúró kó dúró régé, aṣòtítọ’ oní′nú re
ọjọ’ òní le korò díẹ’, ó di dandan k′ọ′la wa ó dára

jọ’wọ′ jẹ ká mú’ra, ká má ṣe ṣiyèméjì
ọjọ′ ọ’la nbọ′, ó nbọ’ wá dùn ṣ’o gbọ′?
ọ′rẹ’ mi m′ọ’kàn le, gb′ójú rẹ s’íbi gíga
ìrètí ògo rẹ nbọ′ wá d’ire

gbọn’ra jìgì, k′o dúró gbágbá
má ì dá′wọ’ dúró ọ′rẹ’ mi ìbẹ′rẹ’ la wà o
taraṣàṣà, má ṣe m′ọ’wọ’ l′ẹ′rán o
báòkú ìṣe ò tán o, l’àwọn àgbà nwí

jọ′wọ’ jẹ ká mú′ra, ká má ṣe ṣiyèméjì
ọjọ’ ọ′la nbọ’, ó nbọ’ wá dùn ṣ′o gbọ′?
ọ’rẹ′ mi m’ọ′kàn le, gb’ójú rẹ s′íbi gíga
ìrètí ògo rẹ nbọ’ wá d’ire

gbọn′ra jìgì, k′o dúró gbágbá
má ì dá’wọ′ dúró ọ’rẹ′ mi ìbẹ’rẹ′ la wà o
taraṣàṣà, má ṣe m’ọ’wọ′ l′ẹ’rán o
báòkú ìṣe ò tán o, l′àwọn àgbà nwí

jọ’wọ′ jẹ ká mú’ra, ká má ṣe ṣiyèméjì
ọjọ′ ọ’la nbọ’, ó nbọ′ wá dùn ṣ′o gbọ’?
ọ′rẹ’ mi m′ọ’kàn le, gb′ójú rẹ s’íbi gíga
ìrètí ògo rẹ nbọ’ wá d′ire

jọ′wọ’ jẹ ká mú′ra, ká má ṣe ṣiyèméjì
ọjọ’ ọ′la nbọ’, ó nbọ′ wá dùn ṣ’o gbọ’?
ọ′rẹ′ mi m’ọ′kàn le, gb’ójú rẹ s′íbi gíga
ìrètí ògo rẹ nbọ’ wá d′ire

ìrètí ògo rẹ nbọ’ wá d’ire
ìrètí ògo rẹ nbọ′ wá d′ire
ìrètí ògo rẹ nbọ’ wá d′ire


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...