lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu beautiful nubia and the roots renaissance band - atonisona

Loading...

ara e wa, e wa gbo tuntun o – yeh!
ara e wa, e wa gbo tuntun o – l’ori oke, won tun gbe de
ara e wa, e wa gbo tuntun o – l’owo isale, won tun gbe de o

ara e wa, e wa gbo tuntun o – ke s’ologbon o, p’on tun ti de o
ara e wa, e wa gbo tuntun o – ke s’awon amoye, p’on tun ti de o

won ni k’a ma fi’fe lo
k’a ma wu wa ‘re
k’a mu’ra s’ohun ti o tun ilu se
k’a ma se so ‘reti nu
k’a so’wo po k’o dara
eniobanke atonisona iye
ara e wa, e wa gbo tuntun o – l’eti okun o, won tun gbe de
ara e wa, e wa gbo tuntun o – ni’nu aginju, won tun gbe de o
ara e wa, e wa gbo tuntun o – ke s’omode o, p’on tun ti de
ara e wa, e wa gbo tuntun o – ke s’awon agba, p’on tun ti de o

won ni k’omo s’ot-to, ko ma se s’aigboran
k’o mu’ra si ise re l’ati kekere
k’a ma se k’egbekegbe, k’a ma ma se’gberaga
eniobanke a ko’mo ni’wa irele

won ni k’a ma s’ot-to, k’a ma wu’wa ‘re
ka mu’ra s’oun ti o tun ‘le yi se
won ni k’a f’ote s’ile, k’a fi’wa s’ola genge
eniobanke a fun ni l’oro agba
ara e wa, e wa gbo tuntun o – ni’bi koro, won tun gbe de
ara e wa, e wa gbo tuntun o – ni gbangba o, won tun gbe de o
ara e wa, e wa gbo tuntun o – ke s’okunrin o, p’on tun ti de o
ara e wa, e wa gbo tuntun o – ke s’awon obirin o, p’on tun ti de


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...