lirik lagu barry jhay - see me see god (smsg)
[intro: chief dr. sikiru ayinde barrister (mfr) & barry jhay]
ẹ maa ka mi mọ wọn, ṣe ni mo da duro
ọrọ mi d’akọ alangba, ko ṣe jẹ ni tutu
koda, ko ṣe china t’ọn gbe ti n jẹ wọn
ẹni j’alangba n tutu, a kó warapa
oh~ah, oh~ah~ah~ah
yeah, ay~ya~ay, ah~ah, ah
oh~wa, oh, wa~wa~wa
(n0body’s perfect)
[verse 1]
yea, k’iku ma~ma pa awọn to gbe mi s’ori bi gele
ki ibanujẹ jina si wa rere, tefe~tefe
k’iku ma p’ọta mi, ko le r’iran wo
(o ri mo fa to n jo, and they no fit hold me, different effect, ah)
ki’ku ma p’ọta mi, ko le r’iran wo
(mo ṣi n m’ẹyẹ bọ lapo, jẹ gbese lapo, ọta mi lo n jẹ gbese, mo mọwọ na)
[pre~chorus]
if i see say wahala don dey too much, na to roll up a big fat one
motivation gan ti n pa’yan, wahala nikan kọ o
ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ (ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ)
[chorus]
see me, see god o, abi emi naa kọ
ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah~yeah
ṣe you dey see level o?
barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yеah, tẹti mọ ọ, ye
[verse 2]
ye, as i dey find wеtin i go chop, ooh~iy
make i no jam wetin go chop me
olúwa lo gbe (yea~yea), lo gbe mi s’oke
emi ko le ṣ’ai ṣope
[chorus]
see me, see god o, abi emi naa kọ
ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah~yeah
ṣe you dey see level o? (ṣe you dey see level o?)
barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (yeah)
yeah, o l’oju ọmọ to damọ
[pre~chorus]
if i see say wahala don dey too much, na to roll up a big fat one
motivation gan ti n pa’yan, wahala nikan kọ o
ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ (ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ)
[chorus]
see me, see god o, abi emi naa kọ
ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah~yeah
ṣe you dey see level o? (ṣe you dey see level o?)
barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (yeah)
yeah, o l’oju ọmọ to damọ
[outro]
sunshine
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu kamaal ibn fareed - picture me
- lirik lagu muillet - reverse
- lirik lagu davìdd - night
- lirik lagu th - lundi
- lirik lagu sidoka - mercedes preta
- lirik lagu youngboy never broke again - drippin’ (2017)
- lirik lagu back yard pimps - r.k.
- lirik lagu ashnebunu - vrum
- lirik lagu мс батон (mc baton) - все пиздят (everybody lies)
- lirik lagu lovv66 - помнишь (remember)