lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu bantu (crew) - jagun jagun

Loading...

[chorus]
jagun~jagun ló ń bọ̀
jagun~jagun ló ń bọ̀
jagun~jagun ló ń bọ̀

[verse 1: chant]
olórí~ogun ò gbọdọ̀ kẹ́yìn ogun
ọ̀kan ṣoṣo ẹja tí ń d’abú~omi rú
ọ̀kan ṣoṣo ẹfọ̀n tí ń d’ọ̀dàn rú
ọ̀kan ṣoṣo àjànàkú tí ń m’igbó kìji~kìji
jagun~jagun dé, ọmọ ọba kìí jagun bí ẹrú
òlọ́ṣọmọ́dìí gba ìbọn lọ́wọ́ ọmọ ojo
jagun~jagun, afiwájúgbọta, afẹ̀yìngbọfà
jagun~jagun ò fẹ́rọ̀, alágbára èyàn tí ń fi májèlé ròfọ́
àlùjànú èyàn tí ń fi ọmọ~odó tayín
bó ṣe ń bá ọmọdé ṣe, bẹ́ẹ̀ ló ń bágbà ṣe
kọ̀nàn~kọ̀nàn já tòun tòwú
jagun~aso, ẹkùn ọkọ òkè!
arọnimaja ṣáagun!
ó ṣáagun ṣáagun, ó ṣáagun títí, ohun l’awo alágbàá`a, èyí tí ó fi ta b’aṣeégún lójú

[chorus]
jagun~jagun ló ń bọ̀
jagun~jagun ló ń bọ̀
jagun~jagun ló ń bọ̀


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...