lirik.web.id
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

lirik lagu anointed mike - ewa re ga

Loading...

call : talaba fi o we, kosi, oluwa, laye lorun

resp: ewa re ga

call: ta lole duro ooo, kosi, nipo re

resp: ewa re ga

call: larin angeli, larin eniyan, kosi ooo

resp: ewa re ga
call: talole pase, kosi, bi tire

resp: ewa re ga

talole soro, kosi, ti yio duro o

resp: ewa re ga

ko lafiwe o, ko lafi jo, ewa re ga

chorus : ewa re ga, koma lafiwe o, (larin awon eniyan, angeli, kolafiwe)x2

female call : ewa re ga o

resp: (ewa re ga)x2 kolafiwe

solo2 :

call : itere

resp : ogo ni

call: ibimimo re

resp: fifun no
call: owo otun re

resp: agbara ni

call: isoro re

resp: iyanu ni

call: irin re

rеsp: ina ni

call: ohun re

resp: ara ni

kolafiwe o, ko lafi jo еwa re ga

chorus : ewa re ga, koma lafiwe o, (larin awon eniyan, angeli, kolafiwe)x2

female call : ewa re ga o

resp: (ewa re ga)x2 kolafiwe


Lirik lagu lainnya:

LIRIK YANG LAGI HITS MINGGU INI

Loading...