lirik lagu annex vodka - idfwu
yea
vodka
yea..
i’m keeping it real for the street
my hittas
fi di haters too…
lets do this
listen
warning
yea; yea;
ebora ni mi; oje gbena, ko tun mi wo;
ole je fire to ma n blaze, buh mo sorry, mi o tun riro;
nkan to kanmi gbon gbon, ni warning yi mode soto o;
die die lese moto nkuro lona, koto wogbo o;
ta ba soro meji, won aso, won a niro la npa;
team oniro, buh, question meji won l’answer;
awa o wule defend; tora mope wonma net wa;
otiye e; oje gangan na fi get wa;
ipe tapejo woku, bawo alaisan be koni ku;
ise ta se indomie, taba se isu be k0ni tu;
abigbehin laaroye, oye komo poma kemi ni;
taba tuni clash, kole temi; oma free mi ni
when dey hear me spit; won a ni dead flows lon fo yen;
toba rimi koja pa; jagaban lo nbo yen;
street ti takeover, so get the h~ll out of my way;
awa ti gba ‘joba, nkan toba wun yin kefiwe;
a lot of hittas, so i gah no time to hate;
heads hating on me, haters faking on me
you ain’t my family
won le n form goliath; shey ka joju yin bi dafidi;
teba tun fe show; ama nail yin mori tabili
won rowo lomi; won tu nbere shoti lowo ni;
kilo jo loju e o, abi shojo paper pool ni;
mi o po loju e, lo se ma nrope o le f~ck m!;
and ti nba jade tan, vampire form e o le suck mi
igboro loga wa, to ba nronu, ko lo binu ku o;
oju e loma she o; ti nba gbona, ti mo n yeruku o;
ti mo nwa pelu awon temi nbariga, ni sh0m~lu o;
to ba be peren; oma jegba lowo eruku o;
eyin temi kitigbe; wo ogbere o
iwo tode damilohun, olorun wasere o;
aye ti gba jeje, e jo e seere o;
awon omo to nwa nsin; walahi, won seree o;
oti mowon lati 2000, awa ti wa lati 1000;
laye alalum0le; ni bust stop, nigba to nma n tosan;
oti dagba nsin; oti ripe; oti deja osan;
ma lo fall victim; oje se sise kotun mosan;
mo n gbona; abi so r0pe mole jona ni;
toba rimi ni street; so rope o le ja na mi;
bere lowo heasyfund; skj, iyen sukanmi;
aye masare su e; toba kan dare po fe fowokan mi;
nigba tan koko rimi, won lebora leleyi maje;
awon kan de sa funmi; won lo n laje ni iya e ma je;
erin yin pami; ati iwo to register, ko nto ma je e;
t’abike ba sa funmi; shey iwo ni ki nwa ma fe;
won joko meji meta, oro mi ni won so;
egbeni lo bustop; shey bo nlemi le fe ma sho;
won le lo nwu, nitori pe gbo pe moti n fresh;
walahi; eshi ma ku, tin ba hit studio pelu lil kesh;
n~gga, n~gga, i don’t f~ck with you;
don’t trynna mess or ama shock that man in you;
(4x)
yea; disturbing africa
vodka
when dey hear me spit; won a ni dead flows lon fo yen;
toba rimi koja pa; jagaban lo nbo yen;
street ti takeover, so get the h~ll out of my way;
awa ti gba ‘joba, nkan toba wun yin kefiwe;
a lot of hittas, so i gah no time to hate;
heads hating on me, haters faking on me
you ain’t my family
won le n form goliath; shey ka joju yin bi dafidi;
teba tun fe show; ama nail yin mori tabili
won rowo lomi; won tu nbere shoti lowo ni;
kilo jo loju e o, abi shojo paper pool ni;
mi o po loju e, lo se ma nrope o le f~ck m!;
and ti nba jade tan, vampire form e o le suck mi
igboro loga wa, to ba nronu, ko lo binu ku o;
oju e loma she o; ti nba gbona, ti mo n yeruku o;
ti mo nwa pelu awon temi nbariga, ni sh0m~lu o;
to ba be peren; oma jegba lowo eruku o;
eyin temi kitigbe; wo ogbere o
iwo tode damilohun, olorun wasere o
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu boa (chl) - sicópata
- lirik lagu sheff g & rich the kid - say that
- lirik lagu kehas - problemas, sonrisa rota
- lirik lagu ckay - christophe marseille
- lirik lagu olympian - around me
- lirik lagu morgxn - wonder
- lirik lagu solaris eve - y al final de mi ausencia
- lirik lagu cesar - oh no !!!
- lirik lagu bigg bravo - firstdayout/suds
- lirik lagu whitney - hammond song