lirik lagu 9ice - possible
yeaaah
palasa o fa, yu dika
so bu ka, fa kaari do
he made the impossibility possible
he made the impossibility possible
oun gbe inu mi baba
oun gbe ninu mi omo
oun gbe ninu mi emi mimo ooo
sa dede ni mo ji, mo ba ila latewo mi
mi o mo eni to ko, ayan mo lo fi ye mi
ahh, baba wo ni ko sese
wo ni baayi ni ma ba ku
baba wa damilare, baba ma je kin jeebi
baba ma fi oju mi rare
baba ma jen je je yi, yiiiiii
he made the impossibility possible
he made the impossibility possible
oun gbe inu mi baba
oun gbe ninu mi omo
oun gbe ninu mi emi mimo ooo
arun tio gba ogun, oluwa ma fi kan mi
arun tio se wo, eleda ma mu ba mi
oun to dun mi lokan, baba je ko di opin
oun ti aye fin bu mi, baba fi funmi
iwo loni ti ba kokun a si
iwo loni bi nba beere wa fi fun mi
ma je, ma je o pe ju, tete se
ma je o pe ju, tete se
olorun iwo nikan lo le se
tete se koma di gobe
eleda ma sun
he made the impossibility possible
he made the impossibility possible
oun gbe inu mi baba
oun gbe ninu mi omo
oun gbe ninu mi emi mimo ooo
in tongues~~~~~~~
he made the impossibility possible
he made the impossibility possible
oun gbe inu mi baba
oun gbe ninu mi omo
oun gbe ninu mi emi mimo ooo
Lirik lagu lainnya:
- lirik lagu croatian amor & lust for youth - sister (club mix)
- lirik lagu bbg baby joe - understand
- lirik lagu young coco - trust nobody
- lirik lagu gator - grip strength
- lirik lagu warhaus - open window
- lirik lagu vinayvvs - new jeans
- lirik lagu sixly - essence
- lirik lagu yung rich cuban - keep it real
- lirik lagu trived & wonnit - cluster
- lirik lagu lilmuillet1 - high lyfe